Top 10 similar words or synonyms for atẹgun

NotFoundError    0.789

Top 30 analogous words or synonyms for atẹgun

Article Example
Kúrùpù Kúrùpù jẹ eyiti a maa nmọ nipa iṣẹ iwadi iṣegun oyinbo. Igbese akoko ni lati yo kuro awọn iṣẹlẹ idiwo ni ọ̀nà-atẹgun oke, papa julọ epiglottitis, oju-ọ̀nà atẹgun nkan ajẹji, subglottic stenosis, angioedema, retropharyngeal abscess, andbacterial tracheitis.
Kúrùpù Awọn ọmọde ti o ni kúrùpù ni a gbọdọ jẹ ki ara wọn balẹ bi o ba ṣee ṣe si. A le fun ni awọn sitẹroidi loorekoore, pẹlu ẹfinifirini ni a nlo fun awọn iṣẹlẹ ti o lewu. Awọn ọmọde ti atẹgun ti o to (iye atẹgun ti a nmi sinu ti o wa ninu ẹjẹ) ti ko to 92% gbọdọ gba atẹgun ti a nmi simu, awọn eniyan ti o ni kúrùpù ti o lewu ni a le da duro si ile-iwosan lati bojuto wọn. Bi atẹgun ti a nmi simu ba nilo, a gba ni niyanju lati lo "blow-by" (mimu orisun atẹgun ti a nmi simu kan sunmọ oju ọmọ naa), nitori kii fa rukerudo bi lilo iboju. Pẹlu abojuto, iye eniyan ti o kere si 0.2% ni o nilo endotracheal intubation(rọba kan ti a maa nfi sinu ọ̀nà-atẹgun .
Kúrùpù Arun fairọsi maa nwo inu awọn sẹẹli ẹjẹ funfun ti o si ma nfa wiwu larynx, trachea, ati ẹ̀dọ̀-f ọ́ọ́rọ́ nla (ọ̀nà-atẹgun ). Wiwu le jẹ ki mi i ki o nira.
Anafilasisi Anafilasisi jẹ [[pajawiri iṣegun oyinbo]] kan ti o le nilo [[titaniji]] bii [[iṣakoso ibiti atẹgun ngba]], afikun atẹgun ti a nmi, ọpọlọpọ [[omi ti o nwa laarin iṣan]], ati abojuto ti o ga gan-an. Fi fun ni ni efinifirini jẹ ààyò abojuto pẹlu alodi si hisatanini ati awọn sitẹriọdu ti a maa nsaba lo gẹgẹ bii asopọmọ. Agba ni nimọran yiyẹniwo fun wakati 2 si 24 ni ile-iwosan fun awọn eniyan l’ọgan ti wọn ba pada si ipo nitori aibalẹ ọkan anafilasisi baifasiki.
Ìmọ̀ Ẹ̀rọ Ìmọ̀ ẹ̀rọ náà ló fáà tí àwọn mọ́tọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ fi dáyé. Àwọn nǹkan amáyédẹrun gbogbo ni ó ti wà. Ẹ̀rọ móhùnmáwòrán, asọ̀rọ̀mágbèsì, ẹ̀rọ tí ń fẹ́ atẹgun (Fan), ẹ̀rọ to n fẹ́ tútù fẹ́ gbígbóná (air condition) Àpẹẹrẹ mìíràn ni ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, alagbeeka, ẹ̀rọ kòmpútà, ẹ̀rọ alukálélukako (Internet).
Anafilasisi Aami aiṣan ni ninu kokoro ara, ara ti njanijẹ, pipọn oju tabi ètè wiwu.Awọn ti wọn ni wiwu tabi wiwu awọ-ara le ṣe apejuwe imọlara ijọna kan l’ara yatọ si ara ti o njanijẹ. Wiwu ahọn tabi ọnafun ni bii 20% awọn eyi ti o waye. Awọn nkan miiran le ni ninu imu ti o nṣe ikun ati wiwu kọnjutifa. Ara naa tun le ni ti o ni àwọ̀ -bulu nitori laisi atẹgun ti a nmi sinu.
Anafilasisi Awọn aami aiṣan ti o rọ mọ mimi le wa, ti o ni ninu aile mi delẹ, mimi ti o ngbọn tabi [idiwọ ọnafun]]. Eemi ti o ngbọn maa nsaba nwaye nipasẹ gbigbọn ti ẹdọ foo eyiti sisunki awọn iṣan maa nfa nigbati mimi ti o wa lati idiwọ ọnafun (stridor) ni asopọ pẹlu didi ọna alafo atẹgun ti oke eyiti o ṣe igbakeji si wiwu. Ohùn kikẹ, irora pẹlu gbigbe nkan mi, tabi ikọ tun le waye.
Kúrùpù Awọn aami aisan kúrùpù ni ninu ikọ́"gbígbó", idiwọ ọnafun(mimi ti o ngbọn), ohun kíkẹ̀, ati mimi ti o nira eyiti o maa nnira ni òru. Ikọ́ "gbígbó" naa ni a maa nsaba ṣ’apejuwe wipe o jọ ìpèerinmi tabi kiniun okun. Si sọkun le mu ki mimi ti o ngbọn naa ki o buru si; mimi ti o ngbọn le tunmọ si wipe ọ̀nà-atẹgun ti dinku. Bi kúrùpù ba ṣe nburu sii, mimi ti o ngbọn le dinku gan-an.
Kúrùpù Kúrùpù ti o mọ niwọnba tabi ti o lewu ṣee ran lọwọ pẹlu nebulized efinifirini(nkan olomi ti a nfa simu lati jẹ ki ọ̀nà-atẹgun le fẹ) Nigbati efinifirine lọpọ igba maa ndin ewu kúrùpù ku laarin iṣẹju mẹwa si ọgbọn (10–30 minutes), awọn anfaani maa npẹ fun bii wakati meji. Bi ipo ba tẹsiwaju lati gberu fun wakati 2–4 lẹyin abojuto ti ti nkan ti ko rọgbọ kankan ko si ṣẹlẹ, omo naa le fi ile-iwosan silẹ.
Kúrùpù Idiye Westley ni ọ̀nà eto ti o wọpọ julọ lati sọ bi kúrùpù ṣe lewu si. A maa nlo ayẹwo yii fun awọn ète iwadi dipo iṣẹ iṣegun oyinbo. O jẹ akọjọ iye awọn aami ti a yan fun awọn abuda marun: ipele imolara, ti o ni àwọ̀-bulu, idiwọ ọnafun, bi atẹgun ṣe nwọle, ati si sunki. Iye aami ti a fi fun ọkọọkan awọn abuda ni a ṣe akọjọ ninu tabili ti o wa lọwọ ọtun, ati iye abajade aami wa laarin oodo si ẹẹtadinlogun (0 to 17).