Top 10 similar words or synonyms for asopọ

ṣalanga    0.997495

iṣoro    0.997282

fifẹ    0.997245

irufẹ    0.997211

tẹle    0.996997

nfe    0.996884

akara    0.996443

ewure    0.996434

ipinnu    0.996324

metali    0.996269

Top 30 analogous words or synonyms for asopọ

Article Example
Anafilasisi Awọn aami aiṣan ti o rọ mọ mimi le wa, ti o ni ninu aile mi delẹ, mimi ti o ngbọn tabi [idiwọ ọnafun]]. Eemi ti o ngbọn maa nsaba nwaye nipasẹ gbigbọn ti ẹdọ foo eyiti sisunki awọn iṣan maa nfa nigbati mimi ti o wa lati idiwọ ọnafun (stridor) ni asopọ pẹlu didi ọna alafo atẹgun ti oke eyiti o ṣe igbakeji si wiwu. Ohùn kikẹ, irora pẹlu gbigbe nkan mi, tabi ikọ tun le waye.
Anafilasisi Bi o ba nilo, a tun le fun ni ni [[Ọna abojuto nipa fifi nkan sinu iṣan| fifi nkan sinu iṣan]] nipa lilo efinifirini olomi ti a ti là. Ṣugbọn a ti ri asopọ mọ [[Cardiac dysrhythmia|dysrhythmia]] ati [[myocardial infarction]]ninu efinifirini ti a fun ni nipasẹ iṣan. [[Abẹrẹ to nfun ni ni efinifirini fun ra rẹ]]ti a nlo fun fifun ara ẹni ni abẹrẹ ni eemeji, ọkan fun awọn agbalagba tabi ọmọde ti iwọn wọn kọja 25 kg ati ọkan fun awọn ọmọde ti iwọn wọn to 10 si 25 kg.
Anafilasisi Gbigbọn ọpa to ngbe ẹjẹ kuro lati ọkan le ṣẹlẹ pẹlu myocardial infarction, aidun deedeti o tẹle, tabicardiac arrest. Awọn ti o ni aiṣan ti ko han sita ninu ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara wa ninu ewu ti o gaju nipa ọkan lati ọwọ anafilasisi. Gbigbọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara nii fiṣe pẹlu wíwà awọn sẹẹli kan ti njọwọ hisitamini sinu ọkan. Nigbati ọkan ti o nyara sáré ti o waye nipase riru ẹjẹ ti o lọ silẹ jẹ eyiti wọpọ, a ti ṣe apejuwe Bezold–Jarisch reflex ni 10% awọn iṣẹlẹ, nibiti ọkan ti o nlọra sáré ti ni asopọ pẹlu riru ẹjẹ ti o lọ silẹ. Lilọ silẹ riru ẹjẹ tabi ijaya (yala [[ ijaya ti o lo kaakiri ara|ti o lo kaakiri ara] tabi [[ijaya ọkan|ti ọkan]) le mu lọwọ imọlara fifuyẹ tabi [[pipadanu òye ìwàláàyè]]. Lilọ silẹ riru ẹjẹ kii saba jẹ aami kansoso fun anafilasisi.
Anafilasisi Anafilasisi le waye ni esi si eyikeyi ohun ajeji. Ohun ti o le faa ti o wọpọ ni ninu [[oró]]lati [[jijẹni ati titani kokoro|jijẹni ati titani kokoro]], awọn ounjẹ, ati [[ogun lilo]]. Ounjẹ ni o wọpọ julọ ti o ma nfaa ninu awọn ọmọde ati ọdọ ṣugbọn ogun lilo ati jijẹni ati titani kokoro ni o wọpọ julọ laarin awọn agbalagba. Awọn okunfa ti ko wọpọ nί ninu: awọn nkan ti eniyan le f’ojuri, nkan ti o niiṣe pẹlu nkan ẹlẹmi bii [[àtọ̀]], oje, ayipada ti o niiṣe pẹlu homoni, awọn afikun ounjẹ bii iyọ oyinbo lati inu ireke ati àwợ ounjẹ (food colors), ati awọn ogun lilo kan.Awọn nkan ti a le f’ojuri bii ṣiṣe idaraya (eyiti a mọ si anafilasisi ti idaraya ṣe okunfa rẹ) tabi iwọn gbigbona tabi titutu (yala gbigbona tabi titutu) le tun ṣe okunfa nipa ipa wọn ni taara lori [[sẹẹli masiti]]. Awọn nkan ti idaraya ṣe okunfa maa nni asopọ pẹlu jijẹ awọn ounjẹ kan. Nigba [[kikunni loorun fun iṣẹ abẹ]], [[neuromuscular blocking agents]], oogun aporo, ati [[oje]] lo wọpọ julọ ti o nfaa. Ninu 32-50% awọn iṣẹlẹ, ohun ti o ṣe okunfa jẹ eyiti a ko mọ idi rẹ, eyiti a npe ni "anafilasisi ti idiopatiki".
Anafilasisi Oriṣi anafilasisi mẹta lo wa. Ayajija ti o niiṣe pẹlu anafilasisi ni asopọ pẹlu [[fifẹ awọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara]]ti o tan kaa kiri gbogbo ara ti o nfa [[riru ẹjẹ ti o lọ silẹ |riru ẹjẹ ti o lọ silẹ]] eyiti o fi 30% lo silẹ ju ila ti o kere julọ tabi iwọn odiwọn itumọ lọ.Anafilasisi ti baifasiki jẹ fifi ara han pada awọn aami aiṣan laarin wakati 1–72 laisi ifarako nkan ti ara korira siwaju. Agbejade iṣẹlẹ yatọ si ara wọn, ti awọn ẹkọ kan njẹwọ irufẹ iṣẹlẹ ti o pọ to 20%. Fifi ara han pada yii maa nsaba waye laarin wakati 8. A maa nṣe abojuto rẹ ni ọna kanna pẹlu anafilasisi. Anafilasisi ti kii ṣe e tootọ tabi abajade anafilasisi ti ko mu awọn aami aiṣan lọwọ jẹ oriṣi anafilasisi ti ko ni awọn abajade nkan ti ara korira ṣugbọn ti o wa ni taara lati ọwọ [[bi sẹẹli ṣe njọwọ granuli]] awọn sẹẹli masiti.Anafilasisi ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara jẹ ọrọ ti [[World Allergy Organization]] nlo lọwọlọwọ pẹlu imọran pe ki a ma lo awọn ọrọ atijọ mọ.