Top 10 similar words or synonyms for apartheid

NotFoundError    0.789

Top 30 analogous words or synonyms for apartheid

Article Example
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): A apartheid :n; (I abhore apartheid) eléyàmèyà Mo kórìíra eléyàmèyà
Walter Sisulu Walter Max Ulyate Sisulu (May 18, 1912 – May 5, 2003) je alakitiyan olodi apartheid ara Guusu Afrika ati omo egbe Kongresi Omoorile-ede Afrika (ANC).
Nelson Mandela Mahatma Gandhi nipa iha ti Mandela ati bi awon ona ti awon alakitiyan olodi apartheid Guusu Afrika fi koju re. (nitori re, Mandela kopa ninu apero oro arofo 29–30 January 2007 ni New Delhi to sajodun odun kewa ti Gandhi se akoso satyagraha (ilodi alainijagidijagan) ni Guusu Afrika).
Albert Lutuli Albert John Lutuli (o tun je kiko bi Luthuli; c. 1898 – 21 July 1967), bakana bi oruko re ni ede Zulu Mvumbi, je oluko ati oloselu ara Guusu Afrika. Lutuli je didiboyan si ipo aare Kongresi Omoorile-ede Afrika (ANC), nigbana bi agbajo ombrela to lewaju ilodi si ijoba akereniye alawofunfun ni Guusu Afrika. O gba Ebun Nobel Alafia ni 1960 fun ipa to ko ninu akitiyan alaije jagidijagan si apartheid. Ohun ni omo Afrika akoko, ati eni akoko ti kii se ara Europe ati ara awon Amerika, to gba Ebun Alafia Nobel.
Nelson Mandela Leyin ti egbe oselu Egbe Omoorile-ede egbe oseluAfrikaner ninu eto idibo odun 1948, nitoripe awon wonyi fowo mo eto apartheid's apartheid's apartheid's eleya-meya, Mandela bere si ni kopa gidigidi ninu oro oselu. O siwaju ninu Kampein Agidi ti ANC se ni 1952 ati ninu Kongresi awon eniyan ni 1955 ti pinu ti abajade re je ipile eto ilodi si ise eleya-meyaanti apartheid. Larin asiko yi, Mandela ati agbejoro re Oliver Tambo da ile-ise agbejoro Mandel's ati Tambo sile lati pese imoran ofin ofe fun opo awon alawodudu ti won ko ni agbejoro.
Erékùṣù Robben Erékùṣù Robben (Geesi: "Robben Island"; Afrikaans "Robbeneiland") je erekusu ni , to je kilomita meje leba Cape Town, ni Guusu Afrika. O je ede Dọ́tsh fun "seal island". Erekusu Robben ri bi oval, 3.3 km gigun lati ariwa de guusu, ati 1.9 km ni fife, pelu aala to je 5.07 km². Pelebe ni, o si je bi mita melo soke ipele omi-okun, nitori agbara-omi to sele nigba ijoun. O kun fun awon okuta ateyinda igba Atetesi Kambria ninu Adipo Malmesbury Group. Erekusu yi se pataki nitoripe ibe ni Aare ile Guusu Afrika ojowaju ati Elebun Nobel Nelson Mandela ati Aare ile Guusu Afrika ojowaju Kgalema Motlanthe, bakanna mo awon elewon oloselu miran, ti lo igba ewon won ni asiko apartheid. Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika lowolowo na lo odun mewa nibe bi elewon.
Nelson Mandela Nelson Rolihlahla Mandela (; Ojó Kejidinlogun Oṣù Keje Odún 1918 - Ojó Karun Oṣù Kejìlá Odún 2013) jé Aare Guusu Afrika láti odún 1994 tìtì di odún 1999, béè sì ni òhun ni Àare Gúusù Afrika àkoko tó jé eni adidiboyan ninu idibo-yani toselu ara ilu asoju yanyan. Ki oto di Aare. Mandela je alakitiyan olodi-apartheid, ati olori Umkhonto we Sizwe, apa adigun Kongresi Omoorile-ede Afrika (ANC). Ni 1962 o di eni afofinmu won si da lebi ika ote ati awon esun miran, won si ran lewon gbere. Mandela lo odun metadin-logbon (27) ni ewon, o lo opo odun yi ni Robben Island. Leyin jijowo re kuro logba ewon ni ojo 11 Osu Keji odun 1990. Mandela siwaju egbe oselu re ninu awon iforojomitorooro to fa oselu awa ara wa ti gbogbo eya ti o waye ni odun 1994, ti o si di Aare orile ede lati odun 1994 titi di 1999. O si sokunfa ifowo-sowopo ni Guusu Afrika, Bakan naa ni a tun mo Mandela si "Madiba", oye eye ti awon Alagba idile Mandela n lo.
Bòtswánà Nigbati Isokan ile Guusu Afrika je didasile bi orile-ede ni 1910 latinu awon ileamusin gbangba Britani ni agbegbe na, Ibiabo Bechuanaland, Basutoland (loni bi Lesotho) ati Swaziland (eyun "High Commission Territories") ko je ara re, sugbon eto wa nigbana lati safikun won lojowaju. Ipinnu ni pe ijiroro yio sele pelu awon alabugbe ibe botileje pe awon ijoba Guusu Afrika mura lati da awon ibi-ile na pada fun won, Britani dina eyi; nitorie ko sele. Idiboyan ijoba Asetolorile-ede ni odun 1948, to pile eto apartheid, ati ikesejade Guusu Afrika kuro ni Egbe Kajola ni 1961, fi opin si ero pe awon ibi-ile yi yio bo si owo orile-ede Guusu Afrika. Ifidimule ijoba britani ati idasile ijoba ibile fa idasile ni 1920 igbimo agbero meji lati soju awon ara Afrika ati ara Europe. awon ikede ni 1934 selana ijoba ati agbara ibile. Igbimo agbero ara Afrika ati ara Europe kan je didasile ni 1951, be sini isepo 1961 selana igbimo asofin adamora.
Nelson Mandela Dere to kuro ni Fort Hare, Jongintaba so fun Mandela ati Justice (to je omo Jogintaba ati eni to kan lati joba) pe ohun ti seto igbeyawo fun awon mejeeji. Sugbo awon mejeeji nitoripe won ko feran eto igbeyawo yi, won kora won si ko lo si Johannesburg. Nigba to de be, Mandela nibere koko ri ise bi asona ninu koto alumoni. Sugbon, eni to gba sise tete yara le kuro nigba to gbo pe Mandela je alagbato Oba. Mandela leyin na bere ise bi akowe ni ile-ise agbejoro to wa ni Johannesburg, Witkin, Sidelsky ati Edelman, lati odo ore ati alawose re, Walter Sisulu. Bo se unsise ni Witkin, Sidelsky ati Edelman, Mandela pari iwe-eri B.A. re ni Yunifasiti Guusu Afrika pelu ifiranse, leyin na lo wa bere si ni gbeko ofin ni Yunifasiti Witwatersrand, nibi to ti bere si ni sore awon elegbe akoko re ati awon alakitiyan olodi apartheid lojowaju Joe Slovo, Harry Schwarz ati Ruth First. Slovo yio wa di Alakoso Oro Ile ninu ijoba Mandela lojowaju, nigbati Schwarz yio di alusoju Guusu Afrika ni Amerika. Ni asiko yi, Mandela gbe ni Alexandra, to wa ni ariwa Johannesburg.