Top 10 similar words or synonyms for anafilasisi

abojuto    0.998274

niiṣe    0.998221

ṣugbọn    0.995150

ẹjẹ    0.995030

itọju    0.994162

ntan    0.993899

kasino    0.993899

sii    0.993398

nṣe    0.993279

ounjẹ    0.992425

Top 30 analogous words or synonyms for anafilasisi

Article Example
Anafilasisi Bi ara ṣe nṣe si nkan kan dale lori bi a ti ṣe nlo ni apakan ati ni apakan awọn abuda ti nkan yii ni ninu. Anafilasisi si pẹnisilini tabi[[sẹfalosiporini]] nikan maa nwaye lẹyin ti wọn ba sopọmọ awọn protini ninu ara ti awọn nkan kan maa ntete sopọmọ pẹlu irọrun ju awọn miiran lọ. Anafilasisi si pẹnisilini maa nwaye ni ẹẹkan ninu 2,000 si 10,000 iṣẹlẹ fun itọju, ti iku si maa waye ni eyiti o kere ju ookan ninu 50,000 iṣẹlẹ fun itọju. Anafilasisi si aspirini ati awọn NSAID maa nwaye ni bii ẹẹkan ninu eeyan 50,000. Bi ẹnikan kan ba ni bi ara rẹ ṣe nṣe si pẹnisilini ti ko dara ewu bi ara wọn yoo ṣe ṣe si sẹfalosporini yoo gaju ṣugbọn yoo si kere sii ookan ninu 1000. Awọn nkan ayẹ ara wo atijọ maa nmu bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi ni 1% awọn iṣẹlẹ nigbati awọn titun maa nmu bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi ni 0.04% awọn iṣẹlẹ wa.
Anafilasisi Oró lati ara awọn kokoro ti nt’ani tabi j’ẹni bii [[Hymenoptera]] (oyin ati agbọn) tabi [[Triatominae]] (kissing bugs) le fa anafilasisi ninu awọn eniyan ti wọn ni ailera sii. Awọn [[Aiṣan_to ntan kaa kiri gbogbo ara|Ṣiṣẹ iṣẹ lodi to tan kaa kiri gbogbo ara], eyiti o jẹ ohunkohun ti o ju bi ara ṣe ṣe ni ayika ibi ti kokoro ti t’ani lọ, eyiti o le jẹ ewu okunfa fun anafilasisi ọjọ iwaju; ẹwẹ, idaji eyiti o ja si iku ko ni bi ara ṣe nṣe lodi ti o tan kaa kiri ara tẹle.
Anafilasisi [[File:Allergy skin testing.JPG|thumb|atanpako|[[Ṣiṣayẹwo nkan ti awọ-ara korira]] ti a nṣe lori apa ọtun]]
Anafilasisi Ninu awọn ti a mọ okunfa wọn ti itoju si wa ni kiakia, asọtẹlẹ rẹ dara. Bi o ti le jẹ wipe a ko mọ okunfa rẹ, bi awọn itọju lati dẹkun ba wa, asọtẹlẹ ma ndara. Bi iku ba waye, o maa nsaba jẹ yala nipa eto mimi (paapaa [[àìlèmí]]) tabi ti ọkan ([[ijaya (lilọ kiri ẹjẹ)|ijaya]]), pẹlu 0.7–awọn isẹlẹ 20% ma nfa iku. Awọn isẹlẹ fifarahan iku laarin iṣẹju ti wa. Awọn abajade ninu awọn to ni anafilasisi ti idaraya nṣe okunfa maa ndara, pẹlu abajade ti o nira ti o kere tabi ti ko nira bi awọn eniyan ti ndagba.
Anafilasisi [[Category:Medical articles translated from English]]
Anafilasisi Lori ipele nipa ayipada ti aiṣan ṣe okunfa ati ẹkọ nipa wọn, anafilasisi maa nwaye nipa jijọwọ awọn olulaja kan lati awọn oriṣi sẹẹli ẹjẹ funfun ti a taji yala nipa ajẹsara tabi awọn eto ti ko nii fiṣe pẹlu ajẹsara. A maa nṣe ayẹwo rẹ nipa awọn aami ti o nfarahan lọwọ lọwọ. Ọna itọju akọkọ ni nipa fi fun ni l’abẹrẹ efinifirini, pẹlu awọn ọna miiran ti o nṣiṣẹ papọ pẹlu rẹ.
Anafilasisi Awọn aami aiṣan ti o rọ mọ mimi le wa, ti o ni ninu aile mi delẹ, mimi ti o ngbọn tabi [idiwọ ọnafun]]. Eemi ti o ngbọn maa nsaba nwaye nipasẹ gbigbọn ti ẹdọ foo eyiti sisunki awọn iṣan maa nfa nigbati mimi ti o wa lati idiwọ ọnafun (stridor) ni asopọ pẹlu didi ọna alafo atẹgun ti oke eyiti o ṣe igbakeji si wiwu. Ohùn kikẹ, irora pẹlu gbigbe nkan mi, tabi ikọ tun le waye.
Anafilasisi Ọpọlọpọ ounjẹ lo le ṣe okunfa anafilasisi; eyi le waye ni igba akoko ti a mọ ti a jẹ ounjẹ yii. Awọn ounjẹ ti o nṣe okunfa kaakiri agbaye yatọ si ara wọn. Ni Iwọ oorun, jijẹ tabi nini ifarakan si ẹpa, wheat, ẹpa ara igi,[[shellfish]], ẹja, wara-olomi, ati ẹyin jẹ awọn okunfa ti o gbalẹ julọ. [[Ekuku]] ni o wọpọ julọ ni Middle East, nigbati irẹsi ati [[chickpeas|chickpea]] maa njẹ orisun anafilasisi ti awọn ara Asia maa nsaba dojukọ. Iṣẹlẹ ti o l’ewu julọ maa nwaye nipa jijẹ ohun ti ara korira (allergen), ṣugbọn awọn eniyan maa nni iriri ti o l’ewu nigbati wọn ba ni ifarakan. Awọn ọmọde le dagba ki wọn bọ lọwọ ohun ti ara wọn korira. Ni bii ọjọ-ori 16, ida awọn ọmọde ti o to 80% ti o ni anafilasisi si wara-olomi tabi ẹyin ati ida 20% ti o ni iriri anafilasisi si ẹpa le farada awọn ounjẹ wọnyii.
Anafilasisi Oriṣi anafilasisi mẹta lo wa. Ayajija ti o niiṣe pẹlu anafilasisi ni asopọ pẹlu [[fifẹ awọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara]]ti o tan kaa kiri gbogbo ara ti o nfa [[riru ẹjẹ ti o lọ silẹ |riru ẹjẹ ti o lọ silẹ]] eyiti o fi 30% lo silẹ ju ila ti o kere julọ tabi iwọn odiwọn itumọ lọ.Anafilasisi ti baifasiki jẹ fifi ara han pada awọn aami aiṣan laarin wakati 1–72 laisi ifarako nkan ti ara korira siwaju. Agbejade iṣẹlẹ yatọ si ara wọn, ti awọn ẹkọ kan njẹwọ irufẹ iṣẹlẹ ti o pọ to 20%. Fifi ara han pada yii maa nsaba waye laarin wakati 8. A maa nṣe abojuto rẹ ni ọna kanna pẹlu anafilasisi. Anafilasisi ti kii ṣe e tootọ tabi abajade anafilasisi ti ko mu awọn aami aiṣan lọwọ jẹ oriṣi anafilasisi ti ko ni awọn abajade nkan ti ara korira ṣugbọn ti o wa ni taara lati ọwọ [[bi sẹẹli ṣe njọwọ granuli]] awọn sẹẹli masiti.Anafilasisi ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara jẹ ọrọ ti [[World Allergy Organization]] nlo lọwọlọwọ pẹlu imọran pe ki a ma lo awọn ọrọ atijọ mọ.
Anafilasisi Anafilasisi jẹ [[pajawiri iṣegun oyinbo]] kan ti o le nilo [[titaniji]] bii [[iṣakoso ibiti atẹgun ngba]], afikun atẹgun ti a nmi, ọpọlọpọ [[omi ti o nwa laarin iṣan]], ati abojuto ti o ga gan-an. Fi fun ni ni efinifirini jẹ ààyò abojuto pẹlu alodi si hisatanini ati awọn sitẹriọdu ti a maa nsaba lo gẹgẹ bii asopọmọ. Agba ni nimọran yiyẹniwo fun wakati 2 si 24 ni ile-iwosan fun awọn eniyan l’ọgan ti wọn ba pada si ipo nitori aibalẹ ọkan anafilasisi baifasiki.