Top 10 similar words or synonyms for alamusin

NotFoundError    0.789

Top 30 analogous words or synonyms for alamusin

Article Example
Sékou Touré Sékou Touré je bibi ni January 9, 1922 sinu ebi awon eniyan Mandinka ni Faranah, French Guinea, lasiko tibe je ohun alamusin ile Fransi. He was an aristocratic member of the Mandinka ethnic group and was the great-grandson of the famous Samory Touré, who had resisted French rule until his capture.
Kóstá Rikà Apa ariwaiwoorun orile-ede yi, Peninsula Nikoya, ni o je ibi guusujulo fun ipa asa Nahuatl nigbati awon olubori ara Spein de be ni orunddun kerindinlogun. Arin ati apaguusu orile-ede ni ipa Chibcha. Sibesibe, awon eniyan atilewa ti kopa lori asa Costa Rican odeoni niye to kere, nitoripe opolopo ninu won ku lowo awon arun bi smallpox ati idamu latowo awon alamusin ara spein.
Victoria, Ṣèíhẹ́lẹ́sì Victoria (nigba miran won npe ni Port Victoria) ni oluilu ile Seychelles (oun ni oluilu Afrika to kerejulo). O budo si egbe ariwa-apailaorun erekusu Mahé, to je erekusu gbangba ni isupoerekusu na. Ilu na koko je didasile bi ibujoko ijoba alamusin Britani. Ni 2009, olugbe re je 25,000 (fun Victoria Berekete, lmupo mo awon itosi-ilu), ninu apapo olugbe 84 000. Victoria ni Papa Ofurufu Akariaye Seychelles (to je pipari ni 1971.)
Pọ́rtúgàl Ni orudnun 15k ati 16k, ntoripe o lewaju Igba Iwari, Portugal di ileobaluaye to nile kakiri Afrika, Asia, Oseania, ati Gusu Amerika, lati di ikan ninu awon alagbara itokowo, oloselu ati ologun lagbaye. Ileobaluaye Portugal ni ileobaluaye akariaye akoko ninu itan, ati eyi to pejulo ninu gbogbo awon obaluaye alamusin Europe. Sibesibe, ipo orile-ede ti je riresile gan titi to fi di orundun 19k, agaga leyin ilominira ile Brasil, to je imusin totobijulo re.
Brasil Brasil tele je imusin Portugal latigba ti Pedro Álvares Cabral gunle sibe ni 1500 titi di 1815, nigba to di ileoba ati Ileoba Asokan Portugal, Brasil ati awon Algafe je didasile. Ibase amusin na je gige ni 1808, nigbati oluilu ileobaluaye alamusin Portugal je gbigbe kuro ni Lisbon lo si Rio de Janeiro, leyin igba ti Napoleon gbogunlu Portugal. Brasil gba ilominira ni 1822 pelu idasile Ileobaluaye ile Brasil, orile-ede abasokan pelu iru ijoba kabiyesi onilanairepo ati sistemu onileasofin. Brasil orile-ede olominira oniare ni 1889, nigba ti ifipagbajoba ologun sakede Orile-ede Olominira, botilejepe ileasofin oniyewu meji, loni to n je Kongresi, ti wa lati igba itowobowe ilanairepo akoko ni 1824. Ilanairepo Brasil loni, to je dida ni 1988, pe Brasil ni Orile-ede Olominira Apapo. Iparapo orile-ede na waye pelu isokan larin Agbegbe Ijoba Apapo, awon Ipinle 26, ati awon Agbegbe ibile 5,564.
Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà Awon eniyan abinibi ti won wa lati Asia ti budo si ori ibi ti orile-ede awon Ipinle Aparapo wa loni fun egberun lopo odun. Awon olugbe Abinibi ara Amerika din niye gidigidi nitori arun ati igbogunti leyin ibapade awon ara Europe. Orile-ede awon Ipinle Aparapo je didasile latowo awon ileamusin metala ti Britani to budo si egbe Okun Atlantiki. Ni ojo 4 Osu Keje, 1776, won se Ifilole Ilominira, eyi kede eto won fun iko araeni ati idasile isokan alafowosowopo won. Awon ipinle asagun yi bori Ileobaluaye Britani ninu Ogun Ijidide Amerika, eyi ni ogun alamusin fun ilominira akoko to yori si rere. Ilana-ibagbepo ile awon Ipinle Aparapo lowolowo je gbigba bi ofin ni ojo 17 Osu Kesan, 1787; itowobosi ni odun to tele so awon ipinle di apa orile-ede olominira kan na pelu ijoba apapo to lagbara. Awon Isofin awon Eto, to ni atunse mewa si ilana-ibagbepo ti won semudaju awon eto ati ainidekun araalu, je titowobosi ni 1791.