Top 10 similar words or synonyms for alaaye

ojise    0.996205

eseese    0.995942

alawujo    0.995514

damoran    0.994501

isotopu    0.994475

marksisti    0.994449

olokiki    0.994324

aaye    0.993889

togajulo    0.993837

ogba    0.993802

Top 30 analogous words or synonyms for alaaye

Article Example
Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le ṣe àtúnṣe ojúewé 184. A kii kere l’aaye eni, a kii tabi laaye alaaye.
Ẹlẹ́ẹ̀mín Ẹlẹ́ẹ̀mín tabi alaaye je sistemu ton min bi eranko, ogbin, ebu ati eleemin tintinni.
Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ tabi Gẹ̀nẹ́tíkì (lati Èdè Gíríìkì aye atijo, γενετικός genetikos, γένεσις genesis, “ibere”) gegebi apa eko baoloji, je sayensi awon abimo, ijogun, ati iyasorisi larin awon adiarajo alaaye.
Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ Ìṣiṣẹ́àbínimọ́ da lori idimu ati imuse oniakinkinni awon abinimo, pelu iwa abinimo ninu ahamo tabi adirajo (f.a. ilagbaralori ati isiseabinimoju), pelu ogun latodo obi si omo, ati pelu ipinkari, iyasoto ati iyipada larin awon olugbe. Nitoripe awon abinibi wa ninu gbogbo awon adirajo alaaye, isiseabinibi se lo lati se akomo gbogbo awon sistemu alaaye, latori awon eran ati bakteria, de ori awon ogbin (agaga awon eso oko) ati awon eran osin, de ori awon eniyan (bi ninu isiseabinibi oniwosan).
Robert G. Edwards Robert Geoffrey Edwards, CBE FRS (ojoibi 1925, Manchester) je ara Britani onimo oro-alaaye ati eni akoko ninu iwosan atunrabi ati oro-alaaye, ati isejile ibimo lode ara (in-vitro fertilization; IVF) lagaga. Pelu onise abe Patrick Steptoe (1913 1988), Edwards se aseyori bibi omo tuntun pelu IVF, eyi fa ibimo omo inu igo akoko, Louise Brown, wa ni 1978. O gba Ebun Nobel fun Iwosan 2010 "fun idagbasoke isejile ibimo lode ara".
Iyọ̀ Awon ioni onikolrini ati sodiomu, ti won je olukopo iyo, se pataki fun iwalaye gbogbo ohun eda alaaye. Iyo nkopa lati samuto water ninu ara. Iyo jijeju le fa ewu fun ilera bi ifunpa eje giga.
Ìjọba ìbílẹ̀ Nàìjíríà Ado-Ekiti (Ado Ekiti), Aiyekite, Efon (Efon Alaaye), Ekiti East (Omuo), Ekiti South West (Ilawa), Ekiti West (Aramoko), Ekiti (Mure), Ido-Osi (Ido Ekiti), Ijero (Ijero), Ikere (Ikere), Ikole (Ekiti), Ileje meje (Eda oniyo), Irepodun/ifelodun (Igede), Ise (Ise), Moba (otun), Oye (Oye Ekiti).
Maurice Wilkins Maurice Hugh Frederick Wilkins CBE FRS (15 December 1916 – 5 October 2004) je omo New Zealand ara Ilegeesi asefisiksi ati asebioloji onihoro, ati elebun Nobel ti iwadi re ko ipa lori oye sayensi ita yanyan, iyasoto isotopu, iwokekere oloju ati X-ray diffraction, ati si idagbasoke radar. O gbajumo fun ise re ni King's College London lori igbamu DNA. Fun ise yi, ohun, Francis Crick ati James Watson gba Ebun Nobel fun Iwosan 1962, "fun iwari nipa igbamu onihoro awon onikikan nukleiki ati pataki re igberin ifitonileti ninu awon eroja alaaye."
Ọ́ksíjìn Nitori pe ohun ni opo isupo omi, oksijin na tun ni opo isupo awon iseelemin alaaye (fun apere, bi meji ninu idameta isupo ara omo eniyan). Gbogbo akosoto ninla awon igbonwo onilepo ninu awon iseelemin alaaye, bi proteins, karboniolomi, ati ora, ni oksijin ninu, bo se je bakanna fun awon adapo alailemin ninla ti won je ike, eyin ati egun awon eranko. Oksijin alapilese unje sise latowo cyanobacteria, algae ati awon ogbin, o si unje lilo ninu imin alahamo fun gbogbo emin tosoro. Oksijin se ipalara si awon iseelemin alailoafefe dandanundandan, ti won je iruida emin atetekose to gbale ni Aye ko to o dipe bere sini pejo ninu afefeojuorun. Iruida miran (allotrope) oksijin, osoni (), seranlowo lati da abo bo igbeojuorun lowo (biosphere) iranka onipupagan pelu ipele osoni ojuibiloke giga, sugbon o je idoti nitosi ojuode nibi ti o ti je eso abe smog. At even higher low earth orbit altitudes atomic oxygen is a significant presence and a cause of erosion for spacecraft.
Ọ́ksíjìn Oksijin je ikan ninu adipo kalkojin lori tabili alakoko, be sini o je apilese alaiseonide highly adarapo gidigidi to unda that readily forms adapo kiakia (agaga awon oloksijin) pelu gbogbo awon apilese yioku. Gegebi isupo re, oksijin ni apilese jantirerejulo keta ni agbalaye leyin haidrojin ati heliom ati apilese tojantirere julo gegebi isupo ninu Earth's crust, o je bi idaji isupo crust. Oksijin adawa je adarapo ni kemika julo lati han ni Aye laisi igbese afimoledapo awon iseelemin alaaye, ti won unlo okun imole orun lati se oksijin alapilese lati inu omi. alapilese sese bere si pejo ninu afefeojuorun leyin ihanjade iyiarada awon iseelemin wonyi, ni bi odun 2.5 billion seyin. Efuufu oksijin oniatomumeji lo je 20.8% itobiaye afefe.