Top 10 similar words or synonyms for akoran

olomi    0.998605

omode    0.997440

nwaye    0.997244

npa    0.997082

afefeayika    0.996688

oku    0.996661

ologbon    0.996653

tumo    0.996134

bakiteria    0.996128

mimu    0.996062

Top 30 analogous words or synonyms for akoran

Article Example
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ẹnsáímù ẹdọ jẹ oriṣirisi ni ibẹrẹ àkÓràn; ní gbígbé gègélé wọn maa n dagba ni ọsẹ meje lehin akoran. Ẹnsaimu ẹdọ ko farajọ àrùn tÓ nípọn. .
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Iye-nísirò akoran kokoro ga ni awọn orilẹ ede kan ni Afrika ati Asia. Awon orilẹ ede ti o ni iye akoran kokoro ti o ga ni Egypt (22%), Pakistan (4.8%) ati China (3.2%). Giga rẹ ni Egypt so mọ ìdádúró ìpolongo ìtọjú gbogbogbòò fun schistosomiasis, lilo abẹrẹ onídígí ti a ko fọ mọ daradara.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C HCV nfa akoran lile laarin àádọta si ọgọrin ninu ọgọrun awon ẹni ti o ni akoran. Lapapọ ida ogoji si ọgọrin ninu ọgọrun awon to ni àrùn na ni o ri ìwὸsan nipa ìtọjú. Ni ọna ti ko wọpọ, akoran le lọ laiṣe itọju. Awọn ti o ni ògbólógbòó àrùn jẹdọjẹdọ C gbọdọ yẹra fun ọtí-líle ati oògùn to lewu fun ẹdọ, ki wọn si gba abęrę àjęsára fun hepatitis A ati hepatitis B. Awọn ti o ni sí-ró-sì-sì gbọdọ ṣe ayẹwo Ọtira-sá-ùnd fun arun ẹjẹ jẹdọjẹdọ.
Ṣiṣunu okunfa ti o wọpọ ni àkóràn ti awọn ifun eyi ti boya àwọn àkóràn, kokoro àkóràn, afomọ, tabi ipo ti a mọsi inu kikun. Awọn akoran yii maa n waye lara ounjẹ tabi omi ti o ni kokoro lara igbẹ, tabi taara lara ẹni ti o ni arun yii. A le pin si ipele mẹta: ṣiṣunu olomi igba kukuru, ṣiṣunu ọlọjọ igba kukuru, ati bi o ba ju ọsẹ meji lọ, ṣiṣunu lemọlemọ. ṣiṣunu olomi igba kukuru lejọ lara akoran ti ṣiṣu ati bibi. Bi o bani ẹjẹ ninu a maa n peni ṣiṣu ẹjẹ. Ọpọ okunfa aini-akoran le di ṣiṣunu ti o pẹlu: hyperthyroidism, aigba ṣuga duro, aarun inu fifẹ, ọpọ ilo oogun, ati aami inu riro ati imi. Ni ọpọ igba awọn aṣa igbẹ ni ako nilo lati jẹri okunfa gan an.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Awọn ti o ni akoran segesege ẹdọ HCV to daju gbọdọ lọ fun itọju. Itọju tó wà bayi jẹ apapọ pegylated interferon ati ogun asodisi kokoro ribavirin fun ọsẹ 24 tabi 48, ti o da lori irufẹ HCV. Abajade to yanranti nṣẹlẹ fun àádọta si ọgọta ninu ìdá ọgọrun awọn eniyan ti a ṣetọju. Àpapọ yala boceprevir tabi telaprevir pẹlu ribavirin ati peginterferon alfa nse iranlowo fun aṣodisi kὸkὸrὸ fun irúfẹ ẹjẹ 1 ti abajade arun jẹdọjẹdọ C. Awon abayọri fun itọju wọpọ; idaji awọn ti a tọju ni, ami ìdánimọ àrùn ayỌkęlę; ati irírí kẹta ní ìṣÒro imọlára. Itọju ni oṣu mẹfa akọkọ dara ju itọju lẹhin ti àrùn jẹdọjẹdọ C ba ti lewu. Bi eniyan kan bani akoran titun ti ko si tii kuro lẹhin oṣu mẹjọ si mejila, a gba iru ęni bęę niyanju lati lo pegylated interferon fun Ọsę mẹrinlelogun. Fun awọn ti o ni talasémíà (a blood disorder), ribavirin dara, ṣugbọn yoo fa gbigba ẹjẹ.