Top 10 similar words or synonyms for airlines

sk    0.996109

columbus    0.994215

aba    0.994076

pennsylvania    0.993869

mississippi    0.993768

olobiri    0.993663

davis    0.993100

dar    0.992776

awori    0.992631

bolívar    0.992609

Top 30 analogous words or synonyms for airlines

Article Example
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró September 11, 2001 Kutukutu ni aro ni ojo 11 osu kesan odun 2001, awon afipagboko mokandinlogun gba idari baalu merin ti won n lo si San Francisco ati Los Angeles lati Boston, Newark, ati Washington, D.C. (Papa Oko-ofurufu Kakiriaye Dulles). Ni ago 8:46 a.m., baalu Ifoloke 11 ti American Airlines fikolu Ile Ariwa ti Gbongan Idunadura Agbaye, o je titele pelu Ifoloke 175 ti United Airlines to kolu Ile Guusu ni ago 9:03 a.m.
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró September 11, 2001 Awon afipagboko keji fi baalu Ifoloke 77 American Airlines kolu Pentagonu ni ago 9:37 a.m. Ifoloko kerin, eyun Ifoloke 93 United Airlines jalulole leba Shanksville, Pennsylvania ni ago 10:03 a.m, leyin ti awon oluwoko ninu baalu yi bere ija pelu awon afipagboko. Won gba pe awon oludaniloro na fe fi lo kolu boya Kapitol (ile to je ti Igbimo Asofin Orile-ede Amerika) tabi White House.
Umaru Farouk Abdul Mutallab Umaru Farouk Abdul Mutallab je omo orile-ede Naijiria to je fifesunkan pe o tiraka lati yin bombu abefanka ninu ifoloke 253 baalu ti Northwest Airlines ni Ojo Keresimesi December 25, 2009.
Badamasi Maccido Badamasi Maccido (1961-2006) je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2003 de 2006 nigba to ku ninu ijanba baalu ADC Airlines Flight 53 pelu baba re Mohammadu Maccido ati omo re.
Mohammadu Maccido Ni ojo 29 Osu Kewa, 2006, Maccido ku ninu ijanba baalu ADC Airlines Flight 53, lati Abuja losi Sokoto lapapo mo opo awon onibise ijoba agba Ipinle Sokoto, ninu won na ni omo re, Badamasi Maccido (alagba asofin) wa, ati eyi tii se omoomo re kan soso.