Top 10 similar words or synonyms for afijuwe

fairọsi    0.996682

tire    0.995703

niyi    0.995520

yara    0.995440

eniti    0.995438

ayewo    0.995349

ese    0.995104

gbagbo    0.994884

imu    0.993873

sibẹsibẹ    0.993816

Top 30 analogous words or synonyms for afijuwe

Article Example
Richard E. Taylor Richard Edward Taylor, CC, FRS, FRSC (ojoibi November 2, 1929 ni Medicine Hat, Alberta) je ojogbon omo Kanada-Amerika ni Yunifasitu Stanford. Ni 1990, o pin Ebun Nobel ninu Fisiksi pelu Jerome Friedman ati Henry Kendall "fun iwadi asiwaju won nipa fifankiri awon elektroni lori protoni ati neutroni, to se pataki fun idagbasoke afijuwe quark ninu fisiksi atasere."
Júpítérì Ini to gbajumojulo ti Júpítérì ni ni Oju Pupa Ninla, iji olodi-ijiyipo to unsele nigbogbo igba to budo si 22° ariwa agedemeji to tobiju Aye lo. O ti je mimo pe o kere ju o wa lati 1831, o se e se ko je lati 1665. Awon afijuwe onimathimatiki da laba pe iji na je lekanlekan ati pe o se e se ko je ini planeti na to wa ni gbogbo igba. Iji yi tobi to be to fun awon telikopu ni Aye ti won ni aperture of tabi titobijubelo le fi seewo.
Ojúọ̀run ayé Afefe je kikopapo nitrijini, oksijini ati argoni ti lapapo won je "awon efuufu pataki" ojuorun. Àwon efuufu yioku ni a mo si "efuufu tasere" (trace gases), lara won ni awon efuufu ogba-alakaba bi omi oru, karboni oloksijinimeji, methani, nitrous oxide ati ossonu. Afefe jijo ni iye tasere opolopo awon adapo alegbogi miran. Opolopo awon ohun ounkoko aladaba le w ninu afijuwe afefe ti ko mo, bi dust, pollen ati spores, sea spray, volcanic ash ati meteoroid. Orisirisi awon amúdọ̀tí ile-ise elero na tun le wa, bi klorini bi apilese tabi adapo, fluorini (ninu adapo), merikuri ti apilese, ati sulferi ninu adapo bi sulferi oloksijinimeji (SO2).
Johannes Hans Daniel Jensen Johannes Hans Daniel Jensen (June 25, 1907 ni Hamburg – February 11, 1973 ni Heidelberg) je ara Jemani to je onimo fisiksi inuatomu. Nigba Ogun Agbaye Keji, o sise lori ise okun inuatomu fun Jemani, to unje Agbo Uraniom, ninu ibi to ti se afikun pataki si ipinya awon isotopu uraniom. Leyin ti ogun pari, o sise bi ojogbon ni Yunifasiti ilu Heidelberg. O tun je ojogbon alejo ni Yunifasiti Wisconsin–Madison, the Institute for Advanced Study, Indiana University, ati the California Institute of Technology. Jensen pin Ebun Nobel ninu Fisiksi odun 1963 pelu Maria Göppert-Mayer fun aba won fun afijuwe igbaeyin inuatomu.
Giordano Bruno Giordano Bruno (1548 – February 17, 1600), oruko abiso Filippo Bruno, je ara Italia elesin Dominiki, amoye, onimomathimatiki ati atorawo, to gbajumo bi elegbe ijeailopin agbalaaye. Awon irojinle oro-ida aye re koja afijuwe ti Koperniku lo nipa pe o pe Òrùn bi ikan ninu awon ohun agbarajo ojuorun alainiye ti won unda lo kiri: ohunni ara Europe akoko to setumo agbalaaye bi ohun ajapo nibi ti awon irawo ti a unri lale ri bakanna bi Orun. O je siseku pa pelu ijona lowo awon alase i 1600 leyin ti Ile Iwadi Romu dalebi esun ailesin to je aibofinmu nigbamo. Leyi iku re o gbajumo gidi; ni orundun 19k ati ibere orundun 20k, awon olutuwo ti won gbe awon igbagbo alatorawo re wo gba bi akoni fun ironu ominira ati awon erookan sayensi odeoni.