Top 10 similar words or synonyms for afefeayika

nwaye    0.998286

npa    0.997495

olowo    0.997461

bakiteria    0.997093

omode    0.997073

oku    0.997054

akoran    0.996688

nitorie    0.996622

laisi    0.996566

iriri    0.996347

Top 30 analogous words or synonyms for afefeayika

Article Example
Júpítérì Júpítérì lo ni afefeayika planeti totobijulo ninu Sistemu Orun, o gun to 5000 km. Nitoripe Júpítérì ko ni ojude, ipile afefeayika re je gbigba bi ojuami ibi ti itemo afefeayika ti dogba mo 10 bars, tabi ona mewa itemo lori Aye.
Árgọ̀nù Árgọ̀nù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo Ar ati nomba atomu 18. O wa ninu egbe 18 (awon efuufu abiire) lori tabili idasiko awon elimenti. Argonu ni efuufu keta to wopo julo ninu afefeayika Aye, ni 0.93% (9,300 ppm), eyi so di eyi to repete ni ona bi 23.8 bi ti efuufu inu afefeayika tto wopo julo to tele, eyun dioksidi karbonu (390 ppm), ati to po repete ni ona to to 500 bi ti efuufu abiire keji to wopo, eyun neonu (18 ppm). Bi gbogbo argonu yi lo je argonu-40 radiogeniki to wa lati ituka potassium-40 ninu igbele Aye. Ni agbalaaye, argonu-36 ni isotopu argonu to wopo julo, nitoripe o je isotopu argonu to je dida pelu stellar ikojonukleu irawo ninu awon supanofa (awon irawo akomonamona).
Òjò oníkíkan Òjò oníkíkan ("Acid rain") je iru ojo tabi iru ìrọ̀sílẹ̀ miran to unsaba je kikan, eyun pe o ni ipele giga awon ioni haidrojin (pH kekere). O le ni ewu si awon ogbin, awon eranko inu omi, ati si ohun miran oriile to ba fon si won. Idie ti ojo kikan se unsele i nitori itujade sulfur oloksijinmeji ati nitrojin oloksijin ti won undarapo mo awon owon omi ninu afefeayika lati da onikikan.
Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004 Athens je yiyan gegebi ilu agbalejo ninu Ipade 106k IOC to waye ni Lausanne ni September 5, 1997. Athens ti kuna idu re lodun meje seyin ni September 18, 1990 ninu Ipade 96k IOC ni Tokyo lati gbalejo Awon Idije Igba Oru 1996 eyi to sele ni Atlanta. abe idari Gianna Angelopoulos-Daskalaki, Athens mura fun idu miran, nigba yi fun eto lati gbalejo Awon Idije Igba Oru 2004. Iyorisirere ilu Athens lati gba awon Idije 2004 da lori ibebe Athens si itan Olimpiki ati itenu re mo ipa pataki ti orile-ede Girisi ati ilu Athens le ko nipa pipolongo iwa Olimpiki ati Isunkankan Olimpiki. Bakanna, ko ri bi idu won fun awon Idije 1996 to je fifi abuku kan fun ailojutu ati iyaju re - nibi ti idu na ko ni unkankan pato, to kan je pe o gbokan le itara ati ero okan pe eto ilu Athens ni lati gbalejo awon Idije ti ogorun odun; idu fun awon Idije 2004 je yiyin fun inirewesi ati ooto re, iranse re to lojutu, ati ekunrere eto idu re. Idu ti 2004 yanju awon isoro ti ti 1996 ko le yanju - pataki imura ilu Athens, idibaje afefeayika re, isuna re, ati ifoselu se ipalemo awon Idije. Iyorisirere Athens nigba to gbalejo Idije-eye Agbaye Ere Ori Papa 1997 losu kan ki idiboyan ilu agbalejo o to waye na tun se pataki nipa imura re lati gbalejo ere-idaraya akariaye. Eyi to tun fa ti won fi yyan ilu Athens ni itara larin awon omo egbe IOC lati da ogo Olimpiki pada si awon Idije, eyi ni won ro pe o sonu nigba Awon Idije Atlanta 1996 ti won fi abuku kan pe o ti je siseju lokowo. Nitorie, iyan Athens je bi ero pe yio yato si awon Idije 1996.