Top 10 similar words or synonyms for abojuto

anafilasisi    0.998274

niiṣe    0.997098

itọju    0.996791

ntan    0.996679

gidigidi    0.994428

ṣugbọn    0.994019

eniti    0.993479

idi    0.993394

agẹrẹ    0.992858

kúrùpù    0.992768

Top 30 analogous words or synonyms for abojuto

Article Example
Streptococcal pharyngitis Awọn aami aisan ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa nsan nipa ṣiṣe abojuto rẹ tabi aiṣe abojuto rẹ, laarin ọjọ mẹta si marun. Ṣiṣe abojuto pẹlu oogun apakokoro maa ndin ewu awọn aisan ti o l’ewu ku ati titan kaakiri aisan naa. Awọn ọmọde le pade si ile-iwe lẹyin wakati mẹrinlelogun (24 hours)ti wọn ba ti lo oogun apakokoro.
Anafilasisi Anafilasisi jẹ [[pajawiri iṣegun oyinbo]] kan ti o le nilo [[titaniji]] bii [[iṣakoso ibiti atẹgun ngba]], afikun atẹgun ti a nmi, ọpọlọpọ [[omi ti o nwa laarin iṣan]], ati abojuto ti o ga gan-an. Fi fun ni ni efinifirini jẹ ààyò abojuto pẹlu alodi si hisatanini ati awọn sitẹriọdu ti a maa nsaba lo gẹgẹ bii asopọmọ. Agba ni nimọran yiyẹniwo fun wakati 2 si 24 ni ile-iwosan fun awọn eniyan l’ọgan ti wọn ba pada si ipo nitori aibalẹ ọkan anafilasisi baifasiki.
Kúrùpù Awọn kotikositẹrọidi, bii desamẹtasone ati budesonide, ṣee lo lati ṣe abojuto kúrùpù awọn ọmọde. A maa nri itura to ni apẹẹrẹ ni bii wakati mẹfa lẹyin abojuto. Bi o ti le jẹ wipe awọn ogun yii nṣiṣẹ nigbati a ba fun ni lati ẹnu (nipasẹ ẹnu), parenteral (nipasẹ abẹrẹ), tabi fi fa si imu, ọ̀nà ti a yan laayo ni nipasẹ ẹnu. Fi fun ni lẹẹkan jẹ gbogbo nkan ti a nilo, eyiti ọpọ si fi ara mọ wipe ko lewu. Desamẹtasone ni idiwọn 0.15, 0.3 ati 0.6 mg/kg tun jọ wipe ohun naa muna doko.
Kúrùpù Ninu ida marundinlọgọrin (75%) iṣẹlẹ parainfluensa fairọsi, oriṣi 1 ati 2, ni fairọsi ti o nfa kúrùpù/laringotrakiatisi ti o lewu gan-an. Awọn fairọsi miiran ti o le fa kúrùpù ni influenza A ati B, measles, adenofairọsi ati respiratory syncytial virus (RSV). Kúrùpù ti o ṣẹlẹ logiji fun igba diẹ (kúrùpù ti o ni gbígbó) maa nwaye nitori iru ẹgbẹ fairọsi kanna bii ti o lewu gan-an laryngotracheitis, ṣugbọn kii saba ni awọn aami arun ti o wọpọ (bii iba, ọ̀nà-ọfun ti o ndun ni, ati sẹẹli ẹjẹ funfun ti o lọ silẹ) ninu. Abojuto, ati idahun si abojuto naa tun jọra.
Anafilasisi A gba ni niyanju lati yẹra fun okunfa anafilasisi. Ni awọn ipo ti eyi ko ti ṣee ṣe, didin bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ku tabi mimu kuro le jẹ eyiti a yan. [[Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni]] pẹlu awọn oro [[Hymenoptera]] jẹ eyiti o f’ẹsẹ mulẹ lati dinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu 80–90% awọn agbalagba ati 98% ninu awọn ọmọde l’odi si awọn nkan ti ara korira [[oyin]], [[agbọn]],[[ agbọn]], [[yelojakẹti]], ati [[tana tana]]. Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni lati ẹnu le munadoko lati dinku tabi mu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu awọn eniyan si awọn ounjẹ kan ti o ninu wara-olomi, ẹyin, ẹpa; ṣugbọn awọn nkan ti ko dara si wọpọ. Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni tun ṣee ṣe fun awọn abojuto ti o pọ, ṣugbọn a gba ọpọ eniyan nimọran lati saa yẹra fun nkan ti o nṣe okunfa naa. Fun awon ti ara won nsise l’odi si oje, o le ṣe pataki lati yẹra fun awọn ounjẹ to nfa ṣiṣe iṣẹ lodi bi pia, ọgede, potato laarin ọpọ ounjẹ miiran.
Kúrùpù A ti ṣe iwadi fun awọn abojuto miiran fun kúrùpù, ṣugbọn ko ti si ẹri ti o to lati ṣe atilẹyin fun lilo wọn. Mimi ikuuku gbigbona simu tabi atẹgun jẹ ọ̀nà atọwọdọwọ lati ṣe abojuto ṣe abojuto ara-ẹni, ṣugbọn awọn ẹkọ iwadi iṣegun oyinbo kuna lati fi mumunadoko mulẹ ati lọwọlọwọ a kii saba lo o. Lilo awọn oogun ikọ́, eyi ti o maa ni dextromethorphan ninu ati/tabi guiafenesin, ni a ko gba ni niyanju lati lo. Nigbati fifa heliox simu (idapọ helium ati oxygen) lati din iṣẹ mimi ku ni a ti lo ni atẹyin wa, ṣugbọn ẹri ti o kere jọjọ lo wa lati ṣe atilẹyin fun lilo rẹ. Nitori kúrùpù lọpọ igba jẹ arun ti fairọsi nfa,awọn oogun apakokoro ni a kii lo a fi bi a ba fura si bakiteria. Apakokoro vancomycin ati cefotaxime ni a gba ni niyanju fun awọn arun bakiteria. Ni awọn iṣẹlẹ ti o lewu ti o rọ mọ ọfinki A tabi B, agbogun ti fairọsi neuraminidase inhibitors ṣee lo.
Anafilasisi Ni igba ikọlu kan, ayẹwo ẹjẹ fun [[tryptase]] tabi [[hisitamini]] (ti jọwọ lati ọwọ awọn sẹẹli masiti) le wulo lati ṣe ayẹwo anafilasisi nitori titani kokoro tabi abojuto. Yatọ si eyi, awọn ayẹwo yii ni ko wulo to bi okunfa ba jẹ ounjẹ tabi bi ẹni naa ba ni [[riru ẹjẹ]] ti o ṣe deedee, wọn kii sii ṣe [[Eyiti a le mọlara tabi mọ ni pato|mọ ni pato]] fun ayẹwo.
Kúrùpù Kúrùpù ti o mọ niwọnba tabi ti o lewu ṣee ran lọwọ pẹlu nebulized efinifirini(nkan olomi ti a nfa simu lati jẹ ki ọ̀nà-atẹgun le fẹ) Nigbati efinifirine lọpọ igba maa ndin ewu kúrùpù ku laarin iṣẹju mẹwa si ọgbọn (10–30 minutes), awọn anfaani maa npẹ fun bii wakati meji. Bi ipo ba tẹsiwaju lati gberu fun wakati 2–4 lẹyin abojuto ti ti nkan ti ko rọgbọ kankan ko si ṣẹlẹ, omo naa le fi ile-iwosan silẹ.
Anafilasisi Bi o ba nilo, a tun le fun ni ni [[Ọna abojuto nipa fifi nkan sinu iṣan| fifi nkan sinu iṣan]] nipa lilo efinifirini olomi ti a ti là. Ṣugbọn a ti ri asopọ mọ [[Cardiac dysrhythmia|dysrhythmia]] ati [[myocardial infarction]]ninu efinifirini ti a fun ni nipasẹ iṣan. [[Abẹrẹ to nfun ni ni efinifirini fun ra rẹ]]ti a nlo fun fifun ara ẹni ni abẹrẹ ni eemeji, ọkan fun awọn agbalagba tabi ọmọde ti iwọn wọn kọja 25 kg ati ọkan fun awọn ọmọde ti iwọn wọn to 10 si 25 kg.
Anafilasisi Awọn eniyan ti o le tete ni anafilasisi ni agba ni imọran lati ni "eto iṣẹ fun nkan ti ara korira si", awọn obi ni agba ni imọran lati fi to awọn ile-iwe awọn ọmọ wọn leti nipa ikọrira ara ati awọn nkan ti o ye ki wọn ṣe bi pajawiri anafilatiki ba ṣẹlẹ. Eto iṣẹ maa nni ninu lilo [[fifun ara ẹni ni abẹrẹ efinifirini]], igbani niyanju lati wọ [[ẹ̀gbà-ọwọ́ itaniji to niiṣe pẹlu iṣegun oyinbo]] kan, ati imọran lati yẹra fun awọn ohun ti o nṣe okunfa. [[Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni lati ṣe bojuto Nkan ti ara korira| Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni]] wa fun awọn ohun ti o nṣe okunfa lati dena anafilasisi ọjọ iwaju. Ẹkọ onilọpọ ọdun nipa didinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu ọra ni ati ri wipe o munadoko lodi si awọn kokoro ti njẹ ni nigbati dinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan lati ẹnu munadoko fun ọpọlọpọ ounjẹ.