Top 10 similar words or synonyms for ọgọrun

òrìsà    0.984657

ìlù    0.983087

funfun    0.981300

ọrọ    0.980240

sẹlẹ    0.980239

mẹta    0.979963

làti    0.979836

ojó    0.979499

ṣíṣẹ    0.976848

ègbón    0.975834

Top 30 analogous words or synonyms for ọgọrun

Article Example
Kúrùpù Bi ida marundinlogun ninu ọgọrun (15%) awọn ọmọde, ti ọjọ ori wọn wa laarin oṣu mẹfa ati ọdun marun si mẹfa (6 months and 5–6 years), yoo ni kúrùpù. Kúrùpù lo maa nfa bi ida marun ninu ọgọrun (5)% awọn ti a gba si ile-iwosan fun ẹgbẹ ti ọjọ ori wọn wa ninu eyi. Ni iṣẹlẹ ti o ṣọwọn, awọn ọmọde ti o kere to oṣu mẹta (3 months) ati ti o dagba to ọdun marundinlogun (15 years) ni kúrùpù. Awọn ọkunrin maa nni idojukọ ida aadọta ninu ọgọrun (50%) ju awọn obinrin lọ; kúrùpù wọpọ ni igba autumn (fall).
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C HCV nfa akoran lile laarin àádọta si ọgọrin ninu ọgọrun awon ẹni ti o ni akoran. Lapapọ ida ogoji si ọgọrin ninu ọgọrun awon to ni àrùn na ni o ri ìwὸsan nipa ìtọjú. Ni ọna ti ko wọpọ, akoran le lọ laiṣe itọju. Awọn ti o ni ògbólógbòó àrùn jẹdọjẹdọ C gbọdọ yẹra fun ọtí-líle ati oògùn to lewu fun ẹdọ, ki wọn si gba abęrę àjęsára fun hepatitis A ati hepatitis B. Awọn ti o ni sí-ró-sì-sì gbọdọ ṣe ayẹwo Ọtira-sá-ùnd fun arun ẹjẹ jẹdọjẹdọ.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Laarin 130 ati 170 milionu eniyan, tabi ~3% ida męta ninu Ọgọrun awọn eniyan agbaye, ni o ni arun jẹdọjẹdọ to lewu. Laarin 3-4 miliọnu eniyan ni o ni arun yii lọdọọdun, ati ju 350,000 eniyan ni o n ku lọdọọdun lati ọwọ arun ti o jẹmọ arun jẹdọjẹdọ C. Iye-nísirò ti pọ gidigidi ni 20th century lori adapọ IDU ati ipoogun intravenous tabi lilo ohun oogun laifọ.
Ọgbẹ́-inú buruli Bí a bá tọ́jú ènìyàn lásìkò, àwọn egbògi agbógun ti àkóràn fún ọ̀sẹ̀ mẹ́jọ a má a ní ipa lórí ìwọ̀n ọgọ́rin nínú ọgọrun (80%) ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn náà. Ìtọ́jú a má a wáyé nípasẹ̀ lílo àwọn egbògi bíi rifampicin àti streptomycin. A tún má a nlo Clarithromycin tàbí moxifloxacin dípò streptomycin. Àwọn ìtọ́jú mìíràn tún lè jẹ́ gígé kúrò ọgbẹ́-inú náà. Lẹ́yìn tí egbò àkóràn náà bá ti jinà, ojú ibẹ̀ a má a ní àpá.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ẹni kan tí ó ní ìpalára gígún abẹ́rẹ́ láti ọ̀dọ̀ ẹni tí ó ní HCV ṣeéṣe kí ó ní àìsàn náà ní bí i ó dín díẹ̀ ní ìdámeji ninu ọgọrun un ìgbà. Ewu náà tún ga sí i tí ó bá jẹ́ pé abẹ́rẹ́ náà bá ní ihò tí ọgbẹ́ náà sí jìn wọnú. Ewu lè wà láti inú kẹ̀lẹ̀bẹ̀ tàbí láti inú ẹ̀jẹ̀; sùgbọ́n ewu yìí kò ga rárá, kò sì sí ewu kan kan rárá bí ó bá jẹ́ pé ara náà kó bó lójú tàbí ní ọgbẹ́.