Top 10 similar words or synonyms for ẹlẹmi

baa    0.997343

iro    0.997000

adie    0.995778

lai    0.995170

ese    0.995159

nse    0.994971

eniti    0.994778

ole    0.994557

ore    0.994211

idanwo    0.993929

Top 30 analogous words or synonyms for ẹlẹmi

Article Example
Streptococcal pharyngitis Ayẹwo nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun ti o ri bẹẹ (ni ọrọ miiran, eyiti o mo wipe eniyan ṣe aisan) tabi ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan, pẹlu awọn aami aisan ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri nfa, nfidi wiwa aisan naa mulẹ. A ko gbọdọ maa ṣe ayẹwo nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun tabi ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan loorekoore fun awọn eniyan ti ko ni aami aisan. Ida awọn eniyan kan l’awujo ni kokoro aifoju lasan ri streptokokal bakiteria naa ninu ọfun wọn lai si abajade ewu kankan.
Streptococcal pharyngitis Ayẹwo kan ti a npe ni mimu nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun (throat culture)ni ọna ti o ṣe koko ju lọ. lati mọ boya eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri. Ayẹwo yii maa nmọ ni ọna ti o daniloju ida 90 si 95 ninu awọn ti o ṣe aisan ti a yẹwo. Ayẹwo kan ti a npe ni ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan (eyiti a tun npe ni ayewo mimọ antigini ni kankan (rapid antigen detection testing), tabi RADT) tun ṣe e lo. Ayẹwo kokoro to nfaa ni kankan yara ju mimu nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun lo sugbọn o maa nmọ aisan daju ninu ida aadọrin ninu ọgọrun (70 percent) awọn eniyan ti ayẹwo. Awọn ayẹwo mejeeji le mọ ni ọgbọọgba nigbati eniyan ko ba ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju ri nfa (ni ida mejidinlọgọrun awọn eniyan ti a yẹwo (98 percent)).
Edgar Adrian O jẹ́ ará ìlu British tí o jẹ́ onímọ ifero mo-ise-ohun-ẹlẹ́mi ati ólùgbà ebùn íyibíye ọlọ́lá ni ọdún 1932 fún ìmọ ìse ohun ẹlẹmi ti oun àti Sir Charles Sherrigbon jùmọ̀ jẹ́ fún ìmúlò oun kan nínú ara tí o má gbé ìròyin làtí ibi opolo de ibi-ti-o kú lárá.
Streptococcal pharyngitis Awọn aami aisan ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa fi ara jọ awọn aami aisan miiran. Fun idi eyi, mimọ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri mọ lai lo nkan ẹlẹmi ti a mu dagba lori nkan amu ẹlẹmi dagba l’ode ara lati ọna-ọfun tabi ayẹwo kokoro to nfa ni kankan le soro. Ikọ́ wiwu, fi fun ikun-imu, igbẹ-ọrin ati oju pipọn ti o nta ni ni afikun pẹlu ibà ati ọna-ọfun to ndun ni le fẹẹ jẹ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri ti fairọsi (virus)fa ju ki o jẹ ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa lọ.
Streptococcal pharyngitis Ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa maa ntan nipasẹ ifarakora pẹkipẹki pẹlu alaisan kan. Lati rii daju wipe eniyan kan ni ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan ri nfa eyiti o ndun ni, ayẹwo kan ti a npe ni mimu awọn nkan ẹlẹmi dagba lori nkan amu nkan ẹlẹmi dagba l’ode ara lati inu ọna-ọfun (throat culture)fun iwadi ṣe pataki. Lai ṣe ayẹwo yii papa ẹwẹ, a le mọ nipa ọna-ọfun to ndun ni ti kokoro ti a ko le f’oju lasan nfa nipasẹ awọn aami aisan. Ni eyiti o jọ bẹẹ tabi ti a mọ daju, awọn apakokoro(antibiotics)(awọn oogun ti o npa bakiteria) le dẹkun aisan naa lati ma l’ewu gan-an ati lati mu ara pada bọ s’ipo ni kiakia.
Anafilasisi [[Charles Richet]] ni o ṣẹda ọrọ "afilasi" ni ọdun 1902 ti o tun wa yipada si "anafilasisi" nitori bi o ti ṣe dun ni sisọ l’ọrọ. O gba aami ẹyẹ [[Aami ẹ̀yẹ Nobel fun Iṣẹ iṣegun ati ẹkọ imọ ijinlẹ ṣiṣe iṣẹ ẹya ara nkan ẹlẹmi (Nobel Prize in Medicine and Physiology]] fun iṣẹ rẹ lori anafilasisi ni ọdun 1913. Iṣẹlẹ naa jẹ eyiti a ti ṣe apejuwe rẹ lati igba lailai.Ọrọ naa wa lati [[ede Giriki|Giriki]] ἀνά ana, "alodi si", ati φύλαξις filasisi, "idaabobo".
Anafilasisi Anafilasisi le waye ni esi si eyikeyi ohun ajeji. Ohun ti o le faa ti o wọpọ ni ninu [[oró]]lati [[jijẹni ati titani kokoro|jijẹni ati titani kokoro]], awọn ounjẹ, ati [[ogun lilo]]. Ounjẹ ni o wọpọ julọ ti o ma nfaa ninu awọn ọmọde ati ọdọ ṣugbọn ogun lilo ati jijẹni ati titani kokoro ni o wọpọ julọ laarin awọn agbalagba. Awọn okunfa ti ko wọpọ nί ninu: awọn nkan ti eniyan le f’ojuri, nkan ti o niiṣe pẹlu nkan ẹlẹmi bii [[àtọ̀]], oje, ayipada ti o niiṣe pẹlu homoni, awọn afikun ounjẹ bii iyọ oyinbo lati inu ireke ati àwợ ounjẹ (food colors), ati awọn ogun lilo kan.Awọn nkan ti a le f’ojuri bii ṣiṣe idaraya (eyiti a mọ si anafilasisi ti idaraya ṣe okunfa rẹ) tabi iwọn gbigbona tabi titutu (yala gbigbona tabi titutu) le tun ṣe okunfa nipa ipa wọn ni taara lori [[sẹẹli masiti]]. Awọn nkan ti idaraya ṣe okunfa maa nni asopọ pẹlu jijẹ awọn ounjẹ kan. Nigba [[kikunni loorun fun iṣẹ abẹ]], [[neuromuscular blocking agents]], oogun aporo, ati [[oje]] lo wọpọ julọ ti o nfaa. Ninu 32-50% awọn iṣẹlẹ, ohun ti o ṣe okunfa jẹ eyiti a ko mọ idi rẹ, eyiti a npe ni "anafilasisi ti idiopatiki".