Top 10 similar words or synonyms for ẹjẹ

anafilasisi    0.995030

nṣe    0.993610

sii    0.993358

ayẹwo    0.993250

niiṣe    0.992921

atẹgun    0.991535

ounjẹ    0.990701

abojuto    0.990203

din    0.989872

gbangba    0.989790

Top 30 analogous words or synonyms for ẹjẹ

Article Example
Anafilasisi Gbigbọn ọpa to ngbe ẹjẹ kuro lati ọkan le ṣẹlẹ pẹlu myocardial infarction, aidun deedeti o tẹle, tabicardiac arrest. Awọn ti o ni aiṣan ti ko han sita ninu ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara wa ninu ewu ti o gaju nipa ọkan lati ọwọ anafilasisi. Gbigbọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara nii fiṣe pẹlu wíwà awọn sẹẹli kan ti njọwọ hisitamini sinu ọkan. Nigbati ọkan ti o nyara sáré ti o waye nipase riru ẹjẹ ti o lọ silẹ jẹ eyiti wọpọ, a ti ṣe apejuwe Bezold–Jarisch reflex ni 10% awọn iṣẹlẹ, nibiti ọkan ti o nlọra sáré ti ni asopọ pẹlu riru ẹjẹ ti o lọ silẹ. Lilọ silẹ riru ẹjẹ tabi ijaya (yala [[ ijaya ti o lo kaakiri ara|ti o lo kaakiri ara] tabi [[ijaya ọkan|ti ọkan]) le mu lọwọ imọlara fifuyẹ tabi [[pipadanu òye ìwàláàyè]]. Lilọ silẹ riru ẹjẹ kii saba jẹ aami kansoso fun anafilasisi.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C . Dida ara wa ni ida 70-80% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 2 ati 3 HCV pẹlu itọju ọsẹ mẹrinlelogun . Dida ara wa ni ida 65% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 4 pẹlu itọju laarin Ọsę mejidinlaadọta. Ẹri itọju arun irufẹ ẹjẹ 6 ko wọpọ, ẹri itọju ti o wa si jẹ bi ọsẹ mejidinlaadọta ni irufẹ iye oògun kanna pẹlu àrùn irufẹ ẹjẹ 1.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Didaraya nipa itọju yatọ gęgębi irúfẹ ẹyà ẹjẹ ti ję. Dida ara fun igba pipę ję 40-50% ninu awọn eniyan ti o ni irufẹ ẹjẹ 1 HCV pẹlu itọju ọsẹ mejidinlaadọta
Anafilasisi Ni igba ikọlu kan, ayẹwo ẹjẹ fun [[tryptase]] tabi [[hisitamini]] (ti jọwọ lati ọwọ awọn sẹẹli masiti) le wulo lati ṣe ayẹwo anafilasisi nitori titani kokoro tabi abojuto. Yatọ si eyi, awọn ayẹwo yii ni ko wulo to bi okunfa ba jẹ ounjẹ tabi bi ẹni naa ba ni [[riru ẹjẹ]] ti o ṣe deedee, wọn kii sii ṣe [[Eyiti a le mọlara tabi mọ ni pato|mọ ni pato]] fun ayẹwo.
Anafilasisi Ninu eto ajẹsara, [[immunoglobulin E]] (IgE) maa nsopọ mọ [[antigini]] (nkan ajeji ti o ru bi ara ṣe nṣe lodi si nkan ti o korira). Antigini-ti o sopọ mọ IgE yoo wa mu olugba[[FcεRI]] ṣiṣẹ lori awọn sẹẹli masiti ati basofili. Eyi yoo wa ṣe okunfa jijọwọ awọn olulaja nkan ti ko tọ bii [[histamini]]. Awọn olulaja yii maa njẹ ki ẹdọ-foo ki [[iṣan didan]] sunki, ta [[fifẹ awọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara]] ji, maa njẹ ki jijo omi lara ẹjẹ inu ọpa-ẹjẹ pọ, ki o si fa irẹwẹsi iṣan ọkan. Eto ajẹsara kan tun wa ti ko da lori IgE, ṣugbọn a ko mọ boya eyi nwaye ninu eniyan.
Kúrùpù Arun fairọsi maa nwo inu awọn sẹẹli ẹjẹ funfun ti o si ma nfa wiwu larynx, trachea, ati ẹ̀dọ̀-f ọ́ọ́rọ́ nla (ọ̀nà-atẹgun ). Wiwu le jẹ ki mi i ki o nira.
Anafilasisi [[Ṣiṣayẹwo nkan ti ara korira]] le ṣe iranlọwọ nipa mimọ ohun ti o nfaa. [[Ṣiṣayẹwo nkan ti awọ-ara korira]] (fun apẹẹrẹ [[Patch test (medicine)|patch testing]]) wa fun awọn ounjẹ kan ati oró. Ṣiṣayẹwo ẹjẹ fun IgE ni pato le wulo lati jẹrisi wara-olomi, ẹyin, ẹpa, ẹpa igi ati awọn nkan ti ara korira ninu ẹja. Ṣiṣayẹwo awọ-ara wa lati jẹrisi awọn nkan ti ara korira bii [[pẹnisilini]] ṣugbọn ko si fun awọn itọju miiran. Iru anafilasisi ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara ṣee mọ nipa itan ati ikọlu si nkan ti ara korira nikan, ti kii si ṣe nipa ayẹwo awọ-ara ati ayẹwo ẹjẹ.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Iṣayẹwo tiṣu Ẹdọ le ṣafihan ipele, tí ẹdọ ti bàjẹ dé ṣugbọn ewu wa ninu ilana yii. Irufẹ awỌn iyàtỌ ti iṣayẹwo tiṣu se àwárí rę ni limfosaites laarin tiṣu ẹdọ, awọn limfọidi foliku ninu pọta tíráyádì, ati awon iyipada si apo ÒrÓ-ǹ-ro. Oriṣirisi ayẹwo ẹjẹ lowa ti o gbiyanju lati safihan ipele idibàję ati ìdínkù ìdí fun iṣayẹwo tiṣu.
Leishmaniasis O le ni ogun orisiri"Lẹṣmania" ti o nse okùnfa àkóràn arun yi lara eniyan. Awon ohun to fa ewu ni: osi, airiounjẹ-jẹ, pipa igbó run, ati kikun-ilu. Orisi mẹtẹẹta lo se e yẹwo labe ẹrọ mikroskopu. Lafikun, arun fisera se e yẹwo nipa ayẹwo ẹjẹ.
Anafilasisi Anafilasisi jẹ nkan ti ara korira si ti o l’ewu kan ti o ma nyara waye ti o si le fa iku. O maa nni awọn abajade aami aiṣan ti o ni ara to njanijẹ gan-an, ọọfun ti o nwu, ati riru ẹjẹ ti o lọ silẹ ninu. Awọn okunfa ti o wọpọ julọ ni ki kokoro j’ẹni/t’ani, ounjẹ, ati oogun.