Top 10 similar words or synonyms for ìyanu

dàbí    0.989503

kéré    0.987058

    0.986660

àbúrò    0.986211

    0.985966

sùn    0.985656

gbó    0.985375

tètè    0.985005

    0.984802

    0.984629

Top 30 analogous words or synonyms for ìyanu

Article Example
Ìrìnkèrindò nínú Igbó Elégbèje Aiyé kún fún ibùgbé ìyanu, ọba bí Ọlọ́rûn kò sí, Olódùmarè ní ńṣe alákǒso ohun gbogbo tí ńbẹ ní òde aiyé àti òde ọ̀run, ìyanu ní aiyé pàápàá jẹ́: aiyé kún fún ènìà ẹlẹ́sẹ̀ méji ati eranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin,ejò afàiyàfà àti ẹja tí ńkákìiri inú omi, ẹiyẹ tí nkọrin bí fèrè àti alágẹmọ tí Olódùmarè wọ̀ ní onírúnrú asọ.Òkè àti pẹ̀tẹ́lẹ̀, oòrùn àti òsùpá, àwọ̀sánmọ̀ àti erùpẹ̀ ilẹ̀,gbogbo ìwọ̀nyí jẹ́ ìyanu.Bákannáà ní ọ̀rọ̀ sìsọ lásán yìí jẹ́ ìyanu, èyítí, mo sì gbọ́ ní ìjọ́sí ni mo ní kí nbá yín sọ lónǐ, ẹ̀nyin ọmọ ènìà..
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): G greet: v; (He greeted me.) (The new idea was greeted with surprise.) ki; yò mó ó kí mi. Jo-kí èrò jo. Èrò tuntun náa jo pèlú ìyanu.
Ìṣekúpa Abraham Lincoln Mo bá oun ìyanu níbẹ̀. Níwájú mi, mo rí pẹpẹ kan tí wọ́n tẹ́ òkú sí tí wọ́n sì fi aṣọ wé. Àwọn ológun dúró ti òkú náàbi pé wọ́n ń ṣọ; ọ̀pò. ènìyàn sì dúró tí wọ́n yọjú wo òkú náà tọ̀fọ̀tọ̀fọ̀, tí wọ́n sì bòó lójú, tí ẹkún sì ń rọ̀ bí òjò
Ẹ̀sìn Búddà Àwọn ohun ti a ri nínú àkọsílẹ̀ ti o ṣe pàtàkì ni pé a bi i ni ọ̀nà ìyanu. Lẹ́hìn ìbí rẹ̀, o dìde dúró ó gbé àwọn ìgbésè nínú èyí tí o kede ara rẹ̀ wí pé òun yoo jẹ́ ìjòyè ayé. O wí pé èyí ni yoo jẹ́ ìgbà ti òun yoo padà wá sáyé gbẹ̀hìn.
Philippe de Champaigne Ó tún ṣiṣẹ́ fún Cardinal Richelieu, tí ó ṣe ẹ̀ṣọ́ Palais Cardinal, tí ó jẹ́ òfúrufú Sorbonne àti àwọn ilé míràn. Champaigne ni oníṣẹ́ ọnà tí wọ́n gbà láàyè loáti ya àwòrán Richelieu tí wọ́n fi sàmì, tí ó ṣe ní ìgbà mọ́kànlá. Ó wà lára àwọn olùdásílẹ̀ Académie de peinture et de sculpture ní ọdún 1648. Nígbà ayé rẹ̀ (láti 1640 síwájú si), ó ṣalábápàdé Jansenism. Lẹ́yìn ìyanu tí ó gbé ọmọ rẹ̀ tí kò lè rìn dìde ní Port-Royal, ó ya àwòrán ẹ̀yẹ yìí "Ex-Voto de 1662", tí ó wà ní Louvre, tí wọ́n fi ṣàpèjúwe ọmọ ayàwòrán yìí pẹ̀lú ìyá olọ́lájùlọ  Agnès Arnauld.
Ẹ̀sìn Krístì Ohun Pàtàkì tí ó jẹ́ ààrin gbungbun èsìn ìgbàgbó tí ó dàbí òpó tí ohun gbogbo dìrò mọ́ ni Jésù . Ìgbàgbọ́ nínú ohun tí Jésù jẹ́ tàbí tí ó ṣe nígbà ayé rè lọ́ bí ìlànà tàbí èkó tí ìjo kọ̀ọ̀kan ń té lè ninu ẹ̀sín ìgbàgbó. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọpọ́lọpọ́ onígbàgbọ́ ló gbàgbọ́ pe ènìyàn ìyanu ni Jésù, àti pé ìṣẹ̀dá rẹ̀ yàtọ sí ti ẹ̀dá alàyè yókù wọn a (àwọn onígbàgbọ) si tún máa kóni láti tẹ̀le àwọn ìkọ̣́ni Jésù, síbẹ̀síbẹ̀, imọ awọn onígbàgbọ́ nipa ohun tí Jésù jẹ́ nítòótọ́ kò jọra wọn. Nítorí ìdí èyí yó ṣe Pàtàkì fún wa láti lo bíbélì ìwé mímọ́ àwon onígbgàgbọ́ làti ṣe atọ̀nà wa nínú àlàyé yìí.
Ẹ̀sìn Krístì Jésù Kírísítì, ni bíbélì tún sọ fún wa pe o jẹ ọmọ ọlọ́run (John 3:16). Jésù fúnrarẹ̀ pe ara rè lọ́mo ọlọ́run nínú ọ̀pòlòpò ẹsẹ̣ bíbélì pàápàá jùlọ nínú àdúrà olúwa tí ó kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ láti máa gbà (Matheu 6:9-13, Luke 11:2-4). Jésú sẹ ọ̀pòḷòp̣ọ̀ iṣẹ́ ìyanu láti fi ìfé olódùmarè hàn sí àwọn ọmọ ènìyàn. Ó lajù afọ́jú, Ó jí okù dìde, Ó mú arọ ní ara dá. Onírúurú ìjọ onìgbàgbọ́ ló ní orísìírísìí ìtumọ̀ fún bibeli torí ìdí eyi onírúrú ìlànà èsìn ni ìjọ kọ̀ọ̀kan ní. Àtí pé ìgbàgbọ wọn nípa ohun tí Jésù jẹ́ yàtọ̀ díèdíẹ̀ síbèsíbè gbogbo wọn gbà pé olùgbàlà ni Jésù. A le ṣe kònkárí àwọn òpó ìgbàgbọ́ tó wà nínú èsìn ìgbàgbọ́ ní ọ̀nà márùn-ún
William Harper (Olóṣèlú ilẹ̀ Rhodesia ) William John Harper (Ọjó kejìlélógún Oṣù keje Ọdún 1916 – Ọjó kẹjọ Oṣù kọkànlá) jẹ́ olóṣèlú, agbaṣẹ́ ṣisẹ́, àtí awakọ̀ òfúrufú ológun Royal Air Force tí ó jẹ́ ìránṣẹ́ óṣèlú ilẹ̀ Rhodesia láti ọdún 1962 sí 1968 tí ó tọwọ́ bọ ìwé tí ìlú náà fí gba òmìnira lati ọwọ́ Gẹ̀ẹ́sì ní ọdún 1965. Wọ́n bíi sí ìdíilé olókìkí oníṣòwò Calcutta tí apá kan obí rẹ̀ jẹ́ Gẹ̀ẹ́sì tí ìkan tókù jẹ́ Índíà, Harper kàwé ní orílẹ̀ èdè Índíà àti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àti pé ó darapọ̀ mọ́ RFA ní ọdún 1937. Ó jẹ́ ọ̀gágun nígbà ogun àgbáyé kejí, tí ó jẹ́ ìkan lára "Àwọn díẹ̀" ní "Ogun Gẹ̀ẹ́sì", tí wọ́n ti paálára lójú ogun. Ó jẹ́ ìyanu fún n nígbà tí Gẹ̀ẹ́sì fún Índíà lómìnirà ní ọdún 1947, ó kọjá sí Rhodesia lẹ́yìn tí ó fẹ̀yìntì nínú ajagun òfurufú lẹ́yìn ọdún méjì síi.