Top 10 similar words or synonyms for ìkànìyàn

trínídád    0.964436

akádẹ    0.953790

ìbílẹ    0.949175

aṣọ    0.947895

agbábọ    0.947680

kíkà    0.946572

ìjọba    0.945754

èkìtì    0.945510

agbègbè    0.944973

ìlà    0.944869

Top 30 analogous words or synonyms for ìkànìyàn

Article Example
Ikenne Ó tóbi tó 144 km² tí àwọn ènìyàn tó ń gbé nínú rẹ̀ sí jẹ́118,735 látàrí ètò ìkànìyàn ti ọdún 2006.
Afghanístàn Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tí wọ́n sọ pé ó wà ní ìlú yìí lé díẹ̀ ní mílíònù mọ́kànlélógún (21,017.000).
Kano Kano jẹ́ olúìlú Ìpínlè Kano àti ìlú tí ó tóbijùlo ẹ̀kẹta ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn ìlú Ìbàdàn àti ìlú Èkó. Gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ọdún 2006, Kano jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní èrò jùlọ ní orílẹ̀̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 137 km2 tí ó sì ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà — Kano Municipal, Fagge, Dala, Gwale, Tarauni àti Nasarawa — pẹ̀lú olùgbélú 2,163,225 ní ìkànìyàn ọdún 2006.
Àwọn Azore Ètò ìkànìyàn 1995 sọ pé ẹgbẹ̀rún lónà ogójì lé ní igba ènìyàn ló ń gbé Azores. Èdè Potokí (Portuguese) ni èdè ìṣe ìjọba ibẹ̀. Wọ́n ti ń lo èdè Gẹ̀ẹ́sì báyìí sí i sá fún èdè ìgbafẹ́ (tourism).
Roubaix Roubaix () jẹ́ atijọ iṣẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì, nítòsí ìlú Tourcoing àti àwọn ààlà pẹ̀lú Bẹ́ljíọ̀m. Agbègbè náà tóbi tó 13.23 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Marseille Marseille () jẹ́ ìlú èbúté ìgbàanì, èyí tá a dá nǹkan bíi 600 ṣááju Sànmánì Tiwa, ní apá gúúsù-ìlàoòrùn Fránsì. Agbègbè náà tóbi tó 240.62 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Parisi Parisi () jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè Fránsì àti ìlú tó tobijulọ nibẹ. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 105.40 km² pẹ̀lú olùgbélú ní ìkànìyàn ọdún 2014.
Villeneuve-d'Ascq Villeneuve-d'Ascq () jẹ́ ìlú tuntun, èyí tá a dá 1970 ní apá àríwá Fránsì. Agbègbè náà tóbi tó 27.46 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Tourcoing Tourcoing () jẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì, nítòsí ìlú Mouscron nílẹ̀ Bẹ́ljíọ̀m àti ìlú Roubaix. Agbègbè náà tóbi tó 15.19 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Àngúíllà Anguilla Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tó wa ní Anguilla jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje àti ọgọ́rùn-ún (7,100). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀. Púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ibẹ̀ ni wọ́n ń sọ èdè Kirió tí wọ́n gbé ka èdè Gẹ̀ẹ́sì (English based Creole). Kirió yìí ni ó wọ́pọ̀ jù ní Áńtílẹ́ẹ̀sì (Lesser Antilles)