Top 10 similar words or synonyms for ìfipá

olá    0.991012

gaara    0.990300

rántí    0.990066

tóka    0.990061

rèé    0.988184

patro    0.987945

ha    0.987925

olorí    0.987449

atégùn    0.987141

ronú    0.987042

Top 30 analogous words or synonyms for ìfipá

Article Example
Ìfipá Gba Maersk Alabama Láìpẹ́, lẹ́yìn tí ó jìyà nínú yàrá ààbò tó móoru yìí fún wákàtí púpọ̀, àwọn atukọ̀ gbìyànjú àti ṣe pàṣípààrọ̀ ajalèlókun tí wọ́n mú pẹ̀lú ọ̀gá ọkọ̀ tí ajalèlókun mú ṣùgbọ́n pàṣípààrọ̀ yìí jásí pàbó, lẹ́yìn tí àwọn atukọ̀ fí ajalèlókun tí wọ́n mú sílẹ̀, àwọn ajalèlókun kọ lati tẹ̀lé àdéhùn. Captain Phillips sin àwọn ajalèlókun wọ ọkọ̀ ojú-omi agbanilà lati fi bí wọ́n ṣe ń wàá hàn wọ́n, ṣùgbọ́n àwọn ajalèlókun fúò sínú ọkọ̀ ojú-omi agbanilà pẹ̀lú Phillips fún owó ìdásilẹ̀
Ìfipá Gba Maersk Alabama Ìfipá Gba Maersk Alabama jẹ́ àtẹ̀léra ìṣẹ̀lẹ̀ orí omi tì ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ajalèlókun mẹrin tí wọ́n fi ipá gba ọkọ̀ ojú omi ẹ̀lẹ́rù, MV Maersk Alabama igbalélógójì máìlí (440 km; 280 mi) gúúsù-ìlàoòrùn Eyl, Somalia. Ìdíwọ́ yìí parí lẹ̀yin akitiyan  Ológun Ojú Omi fún Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà lati gbàwọn sílẹ̀. Ó jẹ́ àkọkọ́ àṣeyọrí ìfipá gba ọkọ̀ ojú omí tí yio ṣelẹ̀́̀ lati bíi ọ̀kànlélógun ọgọrún ọdún sẹ́yìn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyábọ̀ ìròyìn jẹ́ kó di mímọ̀ wípé irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ kẹ́yìn wáyé ní ìgbà Ogun Barbary Kejì ní ọdún 1815, b́ótilẹ̀jẹ́ wípé irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ti wáyé bí ọdún 1821 sẹ́yìn.  Ó jẹ́ ìkẹfà ọkọ̀ ojú omi ẹ̀lẹ́rù, tí àwọn ajalèlókun tí wọ́n ṣẹ̀sẹ̀ gba owó ìdásílẹ̀  rọgùrọ́gù mílíọnù dọ́là máa dojú kọ.
Ìfipá gba Maersk Alabama Ìfipá gba Maersk Alabama jẹ́ àtẹ̀léra ìṣẹ̀lẹ̀ orí omi tì ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ajalèlókun merin tí wọ́n fi ipá gba ọkọ̀ ojú omi ẹ̀lẹ́rù, MV Maersk Alabama igbalélógójì máìlí (440 km; 280 mi) gúúsù-ìlàoòrùn Eyl, Somalia. Ìdíwọ́ yìí parí lẹ̀yin akitiyan  Ológun ojú omi U.S. lati gbàwọn sílẹ̀. Ó jẹ́ àkọkọ́ àṣeyọrí ìfipá gba ọkọ̀ ojú omí tí yio ṣélè́ lati bíi ọ̀kànlélógun ọgọrún ọdún sẹ́yìn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyábọ̀ ìròyìn jẹ́ kó di mímọ̀ wípé irú ìṣẹ̀lẹ̀ bíì tó ṣẹlẹ̀ kẹ́yìn wáyé ní ìgbà Ogun Barbary Kejì ní ọdún 1815, b́ótilẹ̀jẹ́ wípé irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ti wáyé bí ọdún 1821 sẹ́yìn.  Ó jẹ́ ìkẹfà ọkọ̀ ojú omi ẹ̀lẹ́rù, tí àwọn ajalèlókun tí wọ́n ṣẹ̀sẹ̀ gba owó ìdásílẹ̀  rọgùrọ́gù mílíọnù dọ́là máa dojú kọ.
Ìfipá Gba Maersk Alabama Ọkọ̀ náà pẹ̀lú àwọn atukọ mẹ́tàlélógún gbé ẹrù tí ó tó tọ́ọ̀nú 17,000 kọrí sí Mombasa, Kenya lẹ́yìn tí wọ́n dúró ní Djibouti Ní Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹrin Ọdún 2009, àwọn ajalèlókun mẹrin tí ó dá lórí FV Win Far 161 dojúkọ ọkọ̀ yìí. Ọjọ́ orí gbogbo àwọn ajalèlókun mẹ́ẹ̀rin wà láàrín mẹ́tàdínlógún sí ọ̀kàndínlógún, gẹ́gẹ́ bí Akọ̀wé  olùgbèjà U.S. Robert Gates ti ṣàlàyé.
Ìfipá Gba Maersk Alabama Perry dúró sí iwájú yàrá ààbò pẹ̀lú ọbẹ lọ́wọ́, tí ó sì ń dúró de àwọn ajalèlókun tí wọ́n n wá àwọn ẹgbẹ́ atukọ̀ lati gba ṣakóso ọkọ̀ lọ̣́wọ́ wọ́n pẹ̀lú ìgbàgbọ́ pé wọn á wa ọkọ̀ náà lọ sí Somalia. Perry dojú ìjà kọ ọ̀gá àwon ajalèlókun lẹ́yìn tí ó lée mú nínú òkùnkùn ní yàrá ẹ̀rọ. Ọ̀gá àwon ajalèlókun yìí, Abduwali Muse gé ara rẹ̀ lọ́wọ́ nibi tí ó ti n gbìyànjú lati yọ ọ̀bẹ tí Perry fi síi lọ́rùn. Wọ́n di ajalèlókun yìí, Second Mate Ken Quinn sì tọ́jú egbò rẹ̀.