Top 10 similar words or synonyms for ìdásìkò

olórin    0.993756

sístẹ    0.987898

àṣàyàn    0.982419

abùjá    0.981983

ayára    0.980932

amòye    0.976671

nìs    0.976235

òṣeré    0.975605

brítánì    0.975094

fúùfù    0.974687

Top 30 analogous words or synonyms for ìdásìkò

Article Example
Tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì Tabili igba ti je pataki nisinyi ninu imo eko Khemistry, nipa lati pin si owoowo, la si ona to mogbon wa ati lati safiwe awon orisirisi iru iwa egbo. Be na sini tabili yi n je lilo ninu eko Fisiki, Biology, imoero ati Ileise ero. Tabili ise (standard) isinyi ni 117 apilese ti a le fihan gege bi January 27, 2008 (nigbati apilese 118 ti je imudipo (synthesized) apilese 117 ko ti je be).
Tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì Tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì je ona eleto agbehan awon apilese egbo. Bo tile je pe iru tabili yi ti wa tele, eni ti gbogbo eniyan gba pe o da ni onimo khemistry Ararussia Dimitri Mandeleev ni odun 1869. Mandeleev fe tabili yi lati s'afihan ("igba") isele bi a se n da awon apilese mo. Atunse ti bo si iyasile tabili yi, be ni o si ti fe si bi a ba se n seawari awon apilese tuntun be sini a ti se iko apere elero (theoretical model) tuntun la ti se alaye iwuwa egbo.
Tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì Iyasile tabili igba n safihan (igba) isele fun idamo awon egbo. A se akojo awon apilese bi nomba atomu won se n po si (eyun àkọ́wá ati inuikun atomu). Lori ila kanna ni awon apilese ti won ni idamo kanna wa ("akojopo")
Ẹgbẹ́ kárbọ̀nù Ẹgbẹ́ kárbọ̀nù ni ẹgbẹ́ tábìlì ìdásìkò kan tó ní kárbọ̀nù (C), sílíkọ́nù (Si), jẹ́rmáníọ́mù (Ge), tanganran (Sn), òjé (Pb), àti flẹ́rófíọ́mù (Fl).
Kárbọ̀nù Kárbọ̀nù (láti "èédú") je ipilese kemika to ni ami-idamo C ati nomba atomu 6. Gẹ́gẹ́ bí ìkan nínú ẹgbẹ́ 14 lórí tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì, ó jẹ́ aláìjẹ́-mẹ́tàlì àti afagbáramẹ́rindìmú—èyí jẹ́ pé ẹ̀lẹ́ktrọ́nù mẹ́rin wà láti dá ìsopọ̀ kẹ́míkà àjọfagbáradìmú. Àwọn ísótòpù kárbọ̀nù mẹ́ta ni wọ́n wà fún ra wọn, C àti C jẹ́ dídúró, nígbàtí C jẹ́ onítítànyindin, tóúntúká díẹ̀díẹ̀ pẹ̀lú àsìkò àbọ̀-ìgbéayé tó tó bíi ọdún 5,730. Kárbọ̀nù ni ìkan nínú àwọn ẹ́límẹ̀ntì díẹ̀ tí wọ́n ti jẹ́ dídámọ̀ láti ìgbà àtijọ́.