Top 10 similar words or synonyms for áfríkà

túrkì    0.988254

fránsì    0.977343

ọmọẹgbẹ    0.974767

ààrẹ    0.972817

sáyẹ    0.970463

ethiópíà    0.964901

austrálíà    0.963779

apáìwọ    0.962949

gúsù    0.962425

nsì    0.960835

Top 30 analogous words or synonyms for áfríkà

Article Example
Áfríkà Awon orisun itumo miran ti won ti da laba bi orisun oruko ijoun "Afrika":
Áfríkà Afrika ki o to di ibialamusin o se e se ki o ni orisirisi orile-ede otooto to ju 10,000 lo ati asejoba to ni orisirisi ilana ati agbajo oloselu. Ninu awon wonyi ni idipo ebi kekere awon asode bi awon San ni apaguusu Afrika; titobi, awon adipo adimule bi awon idipo ibatan ebi awon elede Bantu ni apaarin ati apaguusu Afrika, awon adipo ibatan adimule gidigidi ni Ibi Iwo Ori Afrika, awon ileoba Saheli titobi, ati awon ilu-orilejoba ati awon ileoba aladawa bi ti awon Yoruba ni Iwoorun Afrika, ati awon ilu oja etiodo awon Swahili ni Ilaorun Afrika.
Áfríkà Awon Almoraffidi, je obairanderan Beriberi lati Sahara ti won fon kiri ariwaapaiwoorun Afrika ati peninsula Iberian nigba orundun 11k. Banu Hilal ati Banu Ma'qil je akopo aon eya Arab Bedouin lati Arabian peninsula ti on kolo si iwoorun lati Egypt larin orundun 11k ati 13k. Ikoreokere fa idapo awon Arabu ati Beriberi, nibi ti awon ara ile ti di Arabu, be sini asa Arabu gba apilese asa ibile ibe, labe isokan Islam.
Áfríkà Afrika bo ibugedemeji mole, o si ni orisirisi awon agbegbe ojuojo; o je orile kan soso to gun lati agbegbe apaariwa aloworo de apaguusu alaworo.
Áfríkà Afrika, agaga gbongan apailaorun Afrika, je gbigba lopolopo latowo awon awujo onisayensi pe ibe ni ibi ti awon eniyan ti bere ati Hominidae clade (great apes), gege bi o se han pelu iwari awon hominids pipejulo ati awon babanla won, ati awon ti won wa leyin won ti won peju bi odun legbegberun meje seyin – lapapomo "Sahelanthropus tchadensis", "Australopithecus africanus", "A. afarensis", "Homo erectus", "H. habilis" and "H. ergaster" – pelu eyi to pejulo ninu won "Homo sapiens" (eniyan odeoni) ti o je wiwari ni Ethiopia to je odun bi 200,000 seyin.
Áfríkà Afri ni oruko awon eniyan ti won gbe ni Ariwa Afrika leba Carthage. Oruko awon wonyi je siso mo "afar" ti awon Finiki, to tumosi "eruku", sugbon ero 1981 kan ti so pe o wa lati oro ede Berber "ifri" tabi Ifran totumosi "cave", in reference to cave dwellers. Afrika tabi Ifri tabi Afer ni oruko Banu Ifran lati Algeria ati Tripolitania (Eya Berber ti Yafran).
Áfríkà Ni ibere Igba Mesosoik, Afrika je jijapo mo awon orile Aye yioku gege bi Pangea. Afrika pin awon fauna kanna ti orilegbangba yi ti o je sisori lowo awon theropods, prosauropods ati ornithischians akokolo nigbati igba Trias wa sopin. Awon idokuta opin je wiwari kakiri Africa, sugbon won wopo ni guusu ju ariwa lo. Ila to ya igba Triassic soto si Jurassic lo falasi ibere awon isele iparun to ni ip ni lagbaye, botilejepe strata Afrika igba yi ko ti je gbigbewo daada.
Áfríkà The countries in this table are categorised according to the scheme for geographic subregions used by the United Nations, and data included are per sources in cross-referenced articles. Where they differ, provisos are clearly indicated.
Áfríkà Awon ipele ile igba Ibere Jurassik pinkiri lona kanna bi ti isun Late Triassic, with more common outcrops in the south and less common fossil beds which are predominated by tracks to the north. As the Jurassic proceeded, larger and more iconic groups of dinosaurs like sauropods and ornithopods proliferated in Africa. Middle Jurassic strata are neither well represented nor well studied in Africa. Late Jurassic strata are also poorly represented apart from the spectacular Tendaguru fauna in Tanzania. The Late Jurassic life of Tendaguru is very similar to that found in western North America's Morrison Formation.
Áfríkà Ife, to je akoko larin awon ilu-orilejoba tabi ileoba Yoruba, sedasile ijoba labe oba, ton unje "Ooni". Ife je ibi pataki esin ati asa ni Afrika, ati fun asa ibile ere gbigbe. Iru ifijuwe ijoba Ile-Ife je gbigbamulo ni Oyo, nibiti awon oba, ti won unje "Alaafin" ti figba kan joba lori opo iye iluorilejoba ati ileoba Yoruba miran ati ti awon ti won ko je Yoruba, "Ileoba Dahomey" awon Fon je ibi ti won ko so ede Yoruba labe ijoba Oyo.