Top 10 similar words or synonyms for àkójopò

akọni    0.991308

àbò    0.988438

òpó    0.987682

bíbélì    0.987366

gbòógì    0.986893

láìpé    0.986198

èkíní    0.986094

ìjèsà    0.985518

onísé    0.984499

brà    0.984292

Top 30 analogous words or synonyms for àkójopò

Article Example
Nọ́mbà àdábáyé Nínú mathematiki, àwon nọ́mbà àdábáyé, tàbí nọ́mbà àdábá (Natural number) lé jé òkan nínú àkójopò {1, 2, 3...} (èyun nọ́mbà odidi rere) tàbí òkan nínú àkójopò {0, 1, 2, 3, ...} (èyun gbogbo nọ́mbà tí kí se tí òdì).
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): H heap: n; (The workmen left a heap of stones in our yand.) akòjopò nnkan gegele. Àwon òsìse náa fi àkójopò àwon òkùta wéwèèwè gegele sílè nínú ogbàà wa.
Àwọn èdè Adámáwá-Ubangi Àkójopò àwon ède kan ni yí tí wón tó márùn-ún-dín-lógósàn-án (175). Wón wà ní apá àríwá ààrin gbùngbùn Aáfíríkà lati apá ìlà oòrùn nàìjíríà títí dé ìwò oòrùn Sùdáànù. Omo egbé Náíjá Kongò (Niger-Congo) ni wón. Wón n pè wón ni Ìla-oòrun Adamawá (Adamawa-Eastern) télè. Díè lára àwon èdè tó wà lábé ìpìn yìí ni Banda Gbanja àti Ngbika.
Síńtáàsì Yorùbá (5ii) Òrò-ìse Àsínpò: Lóòótó àwon tètèdé onígíràmà ti máa ń fún gbólóhùn abódé ní oríkì pé òun ni àkójopò òrò tí ó òrò-ìse kan nínú. Èyí kò wolé mó nítorí a ti rí gbólóhùn abode tí ó ní ju òrò-ìse kan lo. Àpeere irú gbólóhùn abode báyìí ni gbólóhùn alásínpò ìse. Gbólóhùn yìí máa ń ní olùwà kan sùgbón àwon òrò-ìse yìí mó ara won. Òfin ìhun gbólóhùn ti a máa ń lò fún àpólà-ìse inú gbólóhùn alásínpò ise ni.