Top 10 similar words or synonyms for àkàngbé

iÿë    0.984690

ìÿe    0.983020

èrú    0.982781

níjọ    0.982002

èsì    0.979839

ÿíÿe    0.978490

atẹ    0.978221

àgbayé    0.976929

    0.976216

ôdún    0.975988

Top 30 analogous words or synonyms for àkàngbé

Article Example
Kọ́lá Akínlàdé Fólúkẹ́ - Ọmọ Àkàngbé Orímóògùnjẹ́ ni òun náà. Ọmọ ọdún mẹ́wàá ni. Ó ṣẹṣẹ̀ wo kọ́lẹ́jì ni.
Kọ́lá Akínlàdé Ọmọ́wùmí- Ọmọ Àkàngbé Orímóògùnjẹ́ ni òun náà Ọmọ ọdún mẹ́jọ ni. Ilé-ẹ̀kọ́ kékeré ni ó wà.
Kọ́lá Akínlàdé Ọládúpọ̀ - - Ọmọ Àkàngbé Orímóògùnjé ni òun náà. Ọmọ ọdún mẹ́fà ni. Ilé-ẹ̀kọ kékeré ni ó wà. Fólúkẹ́, Omówùmí àti Oládípọ̀ jẹ́ ọmọ Yẹ́wándé. Bándélé jẹ́ ọmọ odún méje. Àṣakẹ́ ni ó bíí Yàtọ̀ sí Àkàngbé Orímóògùnjẹ́, Yéwándé nìkan ni ó tún máa ń mu owó nínú séèfù. Àìsàn Orímóògùnjẹ́ kò ju ọjọ́ mẹ́wàá lọ tí ó fi kú.
Kọ́lá Akínlàdé 2. Túnde Atọ̀pinpin náà kọ lẹ́tà sí Olófìn-íntótó. Ìdẹ̀ra ni orúkọ ilé-ẹ̀kọ́ àbúrò Túndé Atọ̀pinpin. Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún ni Dúró orímóògùnjẹ́. Ẹ̀gbọ́n Ilẹ́sanmí ni Àdùnní ìyá Dúró Orímóògùnjẹ́. Àgbẹ̀ oníkòkó ni Àkàngbé orímóògùnjẹ́, bàbá Dúró nígbà ayé rẹ̀. Túndé Atọ̀pinpin àti ẹ̀gbọ́n rẹ̀ máa ń sùn ní ilé Àkàngbé nígbà ti wọ́n bá ń lọ sí ìhà Odò Ọya. Dúró Orímóògùnjẹ́ nìkan ni ọmọ tí Àdùnní bé. Ará ìlú Àdùnní ni Olófìn-íntótó, ọmọ Adéṣínà. Túndé Atòpinpin máa ń lọ gbé ojà ní Èkó. Ọkọ̀ ojú omi ni ọjà yìí máa ń bá dé.
Kọ́lá Akínlàdé Dúró: Dúró ni àkọ́bí ọmọ Àkàngbé Orímóògùnjẹ́. Ilé-ẹ̀kọ́ girama ni ó wà. Ọdún kan ni ó kù kí ó jáde. Òun ni ó kọ ìwé sí Akin Olúṣínà pé kí ó wá bá òun wádìí owó bàbá òun tí wọn kò rí mọ́. Àdùnní ni orúkọ ìyá rẹ̀ òun nìkan ni ó sì bí fún bàbá rẹ̀. Àdùnní yìí tí kú ní ọdún mẹ́ta ṣáájú bàbá rẹ̀. Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún (17) nì Dúró. Àbúrò mẹ́rin ni ó ní. Àwọn náà ni Àdùkẹ́, Ọmọ́wùmí, Oládípò àti Bándélé.
Kọ́lá Akínlàdé Àkàngbé Ọrímóògùnjẹ́: Òun ni wọ́n jí owó rẹ̀ gbé tí Akin Olúṣínà wá ṣe ìwádìí rẹ̀. Àìsàn tí ó ṣe é tí ó fi kú kò ju ọjọ́ mẹ́wàá lọ. Abẹ́ ìrọ̀rí rẹ̀ ni kọ́kọ́rọ́ ojú ńlá séèfù rẹ̀ máa ń wà. Inú séèfù yìí nì ó máa ń kó owó sí. Kìí yọ àwọn kọ́kọ́rọ́ ojú kékeré séèfù yìí. Tí wọ́n bá ti ilèkùn yàrá rẹ̀, wọ́n máa ń fi kọ́kọrọ́ há orí àtérígbà níbi tí ẹnikẹ́ni ti lè mú un. Orúkọ múràn tí ó ń jẹ́ ni Bándélé. Ogóje náírà (#140), péré ni wọ́n bá nígbà tí ó kú tán. Kí ó tó kú ó ti ra ilẹ̀ tí yóò fi kọ́lè. Ajíṣafínní ni ó bá a dá sí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ tí ó rà náà. Owó Òṣúnlékè ni ó ti rà á. Ẹgbàáta náírà (#6,000) ni ó ra ilẹ̀ náà.
Kọ́lá Akínlàdé 1. Ọmọ ilé-èkọ́ ni Dúró Orímóògùnjé. Ó ku Ọdún kan kí ó jáde ìwé mẹ́wàá. Ìyá rẹ̀ kú ní ọdún mẹ́ta sẹ́yìn, ìyẹ̀n ni pé ó kú ní ọdún mẹ́ta ṣáájú bàbá rẹ̀. Ọmọ ọgọ́ta ọdún ni Bàbá rẹ̀ nígbà tí ó kú. Ikú bàbá rẹ̀ tí ó gbọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ ni o gbé e wálé. Ìyàwó mẹ́rin ni Àkàndé Orímóògùnjẹ́ tí ó jẹ́ ìyá Dúró ti kú, ó ku mẹ́ta. Ọmọ márùn-un ni Àkàńgbé Orímóògùnjé bí Dúró sì ni àgbà gbogbo wọn. Òun ni àkọ́bí. Ìyaa folúké, ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó wọ̀nyí, ni ìríjú àkándé, Orímóògùnjẹ, ìyẹn ni pé òun ni ó fẹ́ran jù. Ìya fólúké yìí ni ó mú kọ́kọ́rọ́ séèfù jáde tí ó ṣí i tí wọn kò sì bá nǹkan kan ní ibẹ̀. Ìgbà tí Àkàndé mú owó kẹ́yìn nínú séèfù yìí kí ó tó kú, owó tí ó wà nínú rẹ̀ ju ẹgbàáta náírà (N30,000.00)lọ. Ọ̀gbẹ́ni Ajúṣefínní: Òun ní ó ra kòkó lówó Àkàngbé. Ó sanwo ní 10/2/80.