Top 10 similar words or synonyms for àjàpadá

wàhálà    0.992824

àwa    0.992119

síse    0.991528

ọpọlọ    0.991338

ọbàlùfọ    0.991236

    0.991209

ìyàtọ    0.990965

lóri    0.990816

ogùn    0.990771

rọrùn    0.990500

Top 30 analogous words or synonyms for àjàpadá

Article Example
Àkúrẹ́ Àjàpadá Aṣọdẹbóyèdé wá jẹ́ ọba ìlú Àkúrẹ́ kìíní, gbogbo ayé gbọ́, ọ̀run sì mọ̀. Iwádìí fi hàn wá pé, Àjàpadá yìí jẹ́ ọmọ Ẹkùn, Ẹkùn sì jẹ́ ọmọ Òdùduwà1. Òdùduwà tí ó jẹ́ bàba Ẹkùn ni ó tọ́jú Àjàpadá dàgbà nítorí Ẹkùn tètè kú. Àjàpadé jẹ́ ọmọ rere, ó sì fẹ́ràn láti máa ṣeré káàkiri ààfin Òdùduwà, àwọn ènìyàn a sì máa pè é ní ‘Àjàpadá Ọmọ Ẹkùn. A gbọ́ pé Odùduwà fún Àjàpadá ní ẹ̀wù oògùn kan tí wọn ń pè ní ‘Ẹ̀wù Ogele’ tí Òduduwà fúnra rẹ̀ fi ń ṣe ọdẹ, nígbà tí Àjàpadá pinnu láti dá ibùgbé tirẹ̀ ní.
Àkúrẹ́ Ohun méjì ni ó mú kí Òdùduwà ṣe èyí, èkínní ni ìwà akíkanjú tí Àjàpadá fi hàn nígbà tí o fi ‘Àjà’1 kékeré pa eku ẹdá nínú ilé àìlujú nígbà èwè rẹ. Èkejì ni ìfẹ́ tí Òdùduwà ní sí Ẹkùn tí ó jẹ́ bàbá fún Àjàpadá. Ẹkùn sì tètè kú, ‘Ọmọ́rẹ̀mílẹ́kún’ ni Àjàpadá jẹ́ sí Odùduwà.
Àkúrẹ́ Ẹ̀bùn ẹ̀wù yìí nìkan kò tẹ́ Àjàpadá lọ́rùn, ó bẹ Odùduwà fún àwọn ohun ọrọ̀ míràn, èyí wá jẹ́ kí Òdùduwà tún rob í baba Àjàpadá ti jẹ́, ó sì wọ ilé lọ, nígbà tí o máa jáde, ó jáde pẹ̀lú ẹwà iwà mímọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ó gbé adé kan lọ́wọ́, ó súre fún Àjàpadá, ó sì sọ fún Àjàpadá pé, ‘mo fi adé yìí jì ọ́’ Mo fi adé jì ọ́, ni ó wá di ‘Déjì’tí o jẹ́ orúkọ oyè ọba ìlú Àkúrẹ́, gẹ́gẹ́ bí ẹni tí Òdùduwà fi adé jì2. Adé yìí jẹ ìtọ́kasí pé ọmọ ọba ni Àjàpadá.
Àkúrẹ́ 1. Ohun èlò ọdẹ ti wọn fi irin ṣe ni o ń jẹ́ ‘Àjà’. Ibi náà ni orúkọ Àjàpadá tí ṣúyọ tí o túmọ̀ sí ‘A fi ajà pá ẹdá (Àjàpadá)
Àkúrẹ́ Ní àsìkò yìí ni àwọn ọmọ Odùduwà ń jẹ ọba káàkiri ilẹ̀ Yorùbá. A gbọ́ pé, Àjàpadá Aṣọdẹ́bọ̀yèdé tí o jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ Odùduwà kúrò ní ìlú Òṣú, ó sì dúró sí ìlú kan tí wọn ń pè ní ‘Òyè’nítòsí Ẹ̀fọ̀n-Alààyè. Rògbòdìyàn, Ìṣòro, ogun àti àìfọkànbalẹ̀ kọ lu ìgbé – ayé Àjàpadá pẹ̀lú ara ìlú ‘Òyè’ náà. Ó wá di dandan fún Àjàpadá láti kúrò ní ìlú ‘Òyè’fún ààbò. Òun àti àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ dórí kọ ilẹ̀ àìmọ̀rí fún ibùgbé.