Top 10 similar words or synonyms for àgbákò

àbímọ    0.925550

tọ    0.922992

    0.921471

péréte    0.914035

nípa    0.913586

àhámọ    0.913112

geere    0.911226

ìṣeọ    0.908824

kóróonú    0.907321

    0.907124

Top 30 analogous words or synonyms for àgbákò

Article Example
Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): P prone, adj. fà sí, tẹ̀ sí (Some people are accident prone) Àwọn ènìyàn kan máa ń fà sí àgbákò
Kọ́lá Akínlàdé Lára wọn ni Ajá to ń Lépa Ẹkùn, Ọ̣wọ̣̣́ Tẹ Amòokùnṣìkà, Àgbákò nílé Tẹ́tẹ́, Baṣọ̀run Olúyọ̀lé, Ajayi, the Bishop, Chaka, the Zulu, Esther, the Queen, Abraham, The…..Friend of God, Sheu Usman Dan fodio, Òwe àti Ìtumọ̀ rẹ̀, Sàǹgbá fọ́, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ó sì tún kópa nínú kíkọ Àsàyàn Ìtàn.
Barack Obama Ní ìgbà èkó rè ní Howard, Obama- àgbà fé Ruth Nidesand, ẹni tí ó bá padà sí orílè èdè Kenya léhìn ìparí èkò rè. Ruth Nidesand jé ìyàwó rè ẹ̀kẹ́ta, wón sì ní ọmọ méjì. Ní orílè èdè Kenya, Obama- àgbà bèrè iṣé ní ilé iṣé tí ó nwa epo ròbì, léhìn èyí, ó ṣiṣé fún ìjọba, gégébí olóòtú ètò ọrò ajé. Ó fi ojú kan ọmọ rè, Obama, ní ìgbàkan péré- ní ìgbà tí oní tòhún pé ọmọ ọdún méwàá. Obama- àgbà fi arapa nínú àgbákò ọkò nípa èyí tí ó sọ ẹsè méjèjì nù. Ní ìgbà tí ó pé ọmọ ọdún mérin-dí-láàdóta, ní ọdún 1982, ó sọ èmí rè nù nínú àgbákò ọkò.
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ C Ọ̀nà àkọ́kọ́ tí àwọn ènìyàn ti máa n ṣe àgbákò àrùn hepatitis C jẹ́ nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀-kan-ẹjẹ̀ ní ìgbà tí ènìyàn bá n gba ìtọ́jú fífa òògùn sínú isan ara, àwọn ohun èlò iṣẹ́ ìlera tí a kò bọ̀ lórí iná kí a tó lò wọn, àti nípa gbígba ẹ̀jẹ̀ sí ara. Ó tó miliọnu 130–170 káàkiri àgbáye tí wọn ní àrùn hepatitis C. Àwọn onímọ̀-ìjìnlẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́-ìwádìí lóri kòkòrò-àrùn HVC ni ààrin ọdún 1970, tí wọn sì fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ọdún 1989 pé àrùn tí n jẹ́ bẹ́ẹ̀ wà. Kò tí ì hàn bóyá kòkòrò náà lè fa àìsàn si ara ẹranko.